Fẹ́ràn bí JésùÀpẹrẹ

Love Like Jesus

Ọjọ́ 13 nínú 13

Fiféràn Bí Jésù

Nígbà tí ebí mi bèrè alágbàtọ́,a lo sí ayẹyẹ Kérésìmesì kan fún àwon òbí alágbàtó tí ṣọ́ọ̀ṣì pèsè èyí tí a kò tiè lè ṣèbẹ̀wò ní èka ìsìn tí a kò sí nínú rè. Mo gbèyìn ní lilo àwon wákàtí méji ni pipaná omijé àti gbigbìyànjú láti múra mi ṣọkàn gírí. Gbogbo ibi ti mo wó mo n sáá kófirí ojú Jésù nínú ogunlọ́gọ̀ èèyàn.

Kódà kí a tó bá àwon omo wa rìn,a pàdé òré tó péwa wá síbi ìgbọ́kọ̀sí. Níbè ni o wà lórí apá rẹ̀ o se rẹ́gí nínú ohun-èlo tí wọn gbé ọmọ ìkókó sí bí ọmọ kékeré obìnrin tí a bí ti ọtí, kokéènì, Xanax, àti àwọn oògùn olóró mìíràn tí mí kò lè rántí. O tún wá mbe nínú ìlèkùn —odindi àgbò àwọn tó yọ̀ǹda ara wọn fi ọ̀yàyà kí wa àti ṣe kìtìkìtì láti pèsè fún wa ni ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ẹrù ìdókòwò àti àwọn ìsàmì orúkọ wọn dípò kín wọn fi Sátidé tó sáájú ọjó Kérésìmesì fi rajà àti jíṣẹ́. Nígbà náà Ọ mbè léyìn wa. Màmá, Bàbá, àti pé rárá mi kò seré, àwọn ọmọ ọdún mẹ́fà tón jé ọmọ-ilé ìwé alágbàtọ. Òpò nínú wọn pèlú àwon ojúdígí tó nípon tàbí àwọn nǹkan tón fi di ẹ̀sẹ̀ mú àti aṣọ to mó àti ẹ̀rín ìtẹ́lọ́rùn. Òun ni onírun pupa tó fi ìyangàn fi hàn mi àwọn ohun ìseré tí àwọn méńbà sóòsì tí a kò mọ̀ orúkọ wọn àti kan dúpẹ lọwọ wọn. Àti pé Òun ní bàbá tó yára nù itó enu ọmọkùnrin tó wa lórí kẹ̀kẹ́ tí won tì kúrò, àti ọmọkùnrin tó nìkan lè dáhùn nípa yiyi ojú rè tó ṣẹṣẹ gbè láti wọ ojú bàbá rè. Àti pé Ọ̀ jé obìnrin tón sòrò pèlú ọmọ ìkókó tó tóbi, onílera tó dára lórí ìbàdí rè àti pé Òun tú jé aròbó tó n se dirodiro láti ẹsẹ rè. Àti obìnrin kan tó tún dàgbà tó n korin fún àwọn ọmọkùnrin kékeré méjì kan pẹ̀lú ohun gbingbin sórí etí kan. Àti Bàbá àgbà, tó dára pèlú fìlà Bàbá Kérésìmesì tó darí orin-Kérésìmesì pẹ̀lú Rudolph àti Jingle Bells so wolé láti jé kára rọ̀ mí àwọn ọmọdé náà. Àti wiwakọ̀ lọ silé pèlú ibi ìkẹ́rùsí tó kún fún àwọn nǹkan ìpápánu àti àwọn ẹbùn tón ṣètorẹ, Mo rí mọ pé Òun ni àwọn obìnrin tẹ̀gbọ́n tàbúrò kékeré méjì tó padà pèlú wa sílé ní alè ojó náà. Kódà Òun tún ni ebi mi náà. A ǹ jé Jésù àti féràn Jésù papó nígbà kan náà. Jésù wá níbi gbogbo tí mo wó. Nínú àwọn tó féràn àti àwọn tí wọn fẹ́ràn.

Ní àyọkà yìí lónìí, Pọ́ọ̀lù ṣẹ́wọ́ sí Sóòsì láti gbé ní ònà tó jé ayẹyẹ àpẹẹrẹ. Pé kí ìbánilò lọ́gbọọgba wa.Pé gbogbo wa lo wa nínú èyí papọ̀. Kìí ṣe awọn ọwọ àti ẹsẹ Rè nìkan, àmó nígbà mìíràn ojú Rè. Ara gidi Rè, tó ṣe kíyè sí i. Àmó àyàfi tí a ba gba ara wa láàyè láti jìnlẹ̀ nínú ìbànújẹ, and àìní, àti ìrora, àti ipò òsì, àti oníròbìnújẹ́, dídánìkan wa, a kò ní ìmọ̀lára rè. àti àwọn ohun bí àwọn ọmọdé ní ládùúgbò rè tó n lọ Kérésìmesì láìsí ẹbí kan kò ní bá ọkàn rè je nítorí o kò ni mò èyíkéyìí nínú orúkọ wọn. Àti tití tí o máa fi wò ojú wọn, o kò ní mọ̀ ìdùnnú rírí Jésù Kristi ojú kò jú lórí apá òrun èyí.

Ó ye náà. Òun ni a ko lè ronú kan, O lẹ́wà gan-an ni!. Òun ni ẹlẹ́rù jẹ̀jẹ̀ àti ọlọ́lá áti ológo àti tàn yinrin. Àti pé ìdí tópò jù bẹẹ lọ láti tó féràn bí Jésù—pẹ̀lú gbogbo ohun tó n mbè nínú wa.

Kendra Golden
Life.Church Creative Media Team

Ìwé mímọ́

Day 12

Nípa Ìpèsè yìí

Love Like Jesus

Báwo ni a ṣe lè kọ́ láti gbé bí Jésù tí a kò bá kọ́kọ́ fẹ́ràn bí Ẹ̀? Máa káa lo pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ àti tọkọtaya Life.Church bí wọn ṣe sọ asòtúnsọ àwọn ìrírí àti àwọn ẹsẹ ọ̀rọ̀ Ìwé Mímọ́ tó fi wọn sábẹ́ ìmísì láti gbé àti fẹ́ràn bí Jésù.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọ̀wọ́ lọ sí www.life.church