Fẹ́ràn bí JésùÀpẹrẹ

Ó Sé Èyí Fún Mi
O jẹ́ ìrólé oṣù kejì tó tutù bí a ṣe dúró sẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà ni àdúgbò wá. Lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà ni ọmọbìnrin kan jókòó sí, ó sunkún pẹ̀lú ìgbóná ara, ó ń wò aṣọ tí kò lápá nìkan àti ṣòkòtò sokoto péńpé. A dúró sẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà, àti mo bó sílè àti sún síhà obìnrin kan tó ń sò pé, “Báwo ni mo ṣe lè ràn ẹ lọ́wọ́?”
Ó ń sọ àwọn ọ̀rọ̀ yìí lábẹ́lẹ̀, “Ó lé mi jáde kúrò nílé. Mo lóyún, àti pé ọ̀rẹ́kùnrin mi lé ní jáde kúrò nílé.”
Bí ń mọ ń ṣe wà àwọn ọ̀rọ̀, my only thought èrò mi ni pé, èèyàn ni. Bọ̀wọ̀ fun un. Torí náà ni béèrè, “Kí ni orúkọ rẹ̀?”
“Brittney.”
Mo dáhùn, “Ó dára gidi gan láti pàdé ẹ, Brittney. Se wà fẹ́ kí ọkọ̀ gbé ẹ lọ síbi tó ń lọ?”“Béèni, ìyá àgbà mì ń gbé nítòsí.” ó sò.
A rìn lọ sínú okò, àti ọkọ mi sí fò sórí ìjókòó èyín pẹ̀lú àwọn ọmọ wa méjèèjì – tó ń jó jókòó pẹ̀lú ojú àti ẹnu ni ìfẹ́. Láì pàdánù ilú kan, mo dárúkọ ẹbí mi fún Brittney bé ni pé mo ti mọ̀ fún ọdún her for years.
“Brittney, ṣe ó má dára tí mo bá mú aṣọ wá fún ẹ? Mo kan lè sáré wọlé lọ kín mú wọn wá.”ll?”
“Bẹ́ẹ̀ ni, òtútù ń mú mi gidi gan-an.”
Mo dúró sẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà tí okò ń gbà àti mo sí wọlé lọ. Sí ìyàlẹ́nu mi, Brittney tè lé mi lẹ́yìn. Mo mú ẹ̀wù alápá gígùn, ṣòkòtò tó ń dènà òtútù, àti bàtà róbà. Mo kọ àwọn aṣọ yẹn fún un, ó ṣi wọnú ìyára ìtura láti pààrò aṣọ rè.
Nígbà náà a mú lọ silé ìyá àgbà rè àti sọ pé ó dàbọ̀. Nígbà tí a ń lo lé, àwọn ọmọ wa béèrè nípa ohun tó ṣe ṣẹlẹ̀, Mo kan sọ pé, “Ó dá mi lójú pé ohun tí Jésù má tí fẹ́ kí a sé nìyẹn.” Wọn gbà, a sí bá ìyókù ìrólé wa lọ.
Òwúrò ọjọ́ kejì, mo kan kà ìfọkànsìn mi nígbà tí ó dà bẹ́ ni pé àwọn ọ̀rọ̀ fò sókè lójú ìwé, “Mo wà ní ìhòòhò ìwọ sì fi fún mi.” ọkàn mi yára sókè bí mo ṣe rántí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ álẹ́ ọjọ́ tó ṣáájú.
Àwọn àǹfààní láti fẹ́ràn bí Jésù lè ṣẹlẹ̀ nígbàkigbà, níbikíbi. A lè fẹ́ràn statnger lórí bí bí Jésù láì orúkọ orúkọ rè. Nígbà tí Brittney pàdé Jésù, Mo gbàdúrà pé ó máa dá A mò gẹ́gẹ́ bí Ẹnì tí òun pàdé lójú ọ̀nà rè silé ìyá àgbà rè ni ìrólé olọ́tútù ni Osù kejì kan.
Tasha Salinas
Life.Church Midwest City
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Báwo ni a ṣe lè kọ́ láti gbé bí Jésù tí a kò bá kọ́kọ́ fẹ́ràn bí Ẹ̀? Máa káa lo pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ àti tọkọtaya Life.Church bí wọn ṣe sọ asòtúnsọ àwọn ìrírí àti àwọn ẹsẹ ọ̀rọ̀ Ìwé Mímọ́ tó fi wọn sábẹ́ ìmísì láti gbé àti fẹ́ràn bí Jésù.
More