Fẹ́ràn bí JésùÀpẹrẹ

Love Like Jesus

Ọjọ́ 7 nínú 13

Didúró Lórí Ilà Ní Bánkì

Ipò láwùjọ máa ń kàyéfì mi nígbà gbogbo. Kí nìdí tí àwọn èèyàn máa ń fí gbé àwọn èèyàn kan ga láì gbé àwọn mìíràn ga? Òpò nǹkan lè wà tó nípá lórí ipò èèyàn lórí òpá òòsà tí àwùjọ: okíkí, ọró, agbára ìlèse, ẹwà, ìwà ẹni, orúkọ oyè, ogún, àti béè béè lo.

O ṣeé ṣe kó jé láàrín ilé ẹ̀kọ́ girama ní mo kókó sàkíyèsí onírúurú ipò gbígbajúmọ̀, àmó bí mo se dàgbà mo tèsíwájú láti máa sàkíyèsí pé ogúnlógò àwọn èèyàn fìmọ̀ṣọ̀kan lọ fún àwọn kan, àtipe lápapò pá àwọn yòókù tì. A fún ara wa ní ipò, a fí àwon kan síwájú àti àwọn yòókù sikéyìn.

Ní ọdún àkókó léyìn tí mo kó lọ sílù ńlá, Mo ṣe àṣìṣe òmùgò kan láti lọ sídí èro tó n gbowó tó sì ń sanwó ní báńkì lójó Sátidé. Lójú ònà mi láti pàdé ení àjọròde mi tí Mọ nírètí látiwú lórí Mọ gbà ipò mi lórí ìlà tó gùn tí àwọn èèyàn àláììnísùúrù tó nílo owó fún òpín òsé. Mọ sọnú sínú èrò, Mi kò tètè sàkíyèsí rògbòdìyàn tó ń gbèrù níwájú ìlà tó ní o kéré jù lọ bí àwọn èèyàn bí mẹjo. Ení tó ń sunkún àti gbólóhùn abúru gbà afíyèsí mi, àmó, mo sàkíyèsí obìnrin onírun tín-ín-rín tón tiraka láti kápa àwọn èrò ìmọ̀lára rè àti parí ìdúnàádúrà rè. Mo tẹjú mó obìnrin náà, àtipe nígbà náà mo wo ilà àwọn èèyàn tó wà níwájú mi àti ìlà àwọn èèyàn tó wà léyìn mi. Gbogbo èèyàn yẹra fún wíwo ojú ara won, àti nípa ìwà réré (tàbí o kan jé àìnísùúrù ní gbangba) pa obìnrin tó wà nínú wàhálà náà tì. Obìnrin náà fági lé ìdúnàádúrà rè, léyìn náà o kojú sí gbogbo wa o sò wípé, “Bàbá Mi sese kọjá lọ.” kò fí béè dá bí àforíjì, àti pé o fé dá bí àlàyé. Nígbà tí kò gbà ìdáhùn padà, o yíjú padà, o yin sunkún, àtipe o korí sínú ibi ìgbọ́kọ̀sí. Mo wo àyíká fún ẹnìkan láti ṣe ìrànlọ́wọ́, Mo rò pé o yé kí ẹnìkan ṣe nǹkan. Sí ìríra Mi, o se wá yẹ Mi nígbà náà pé ìdí tí esè mi fi fìdí múlẹ̀ sílè ní pé Mi kò fé pàdánù ipò Mi lórí ìlà tó ń gún sí.

Ìgbà melo lan se ìje pàtàkì àwọn àjẹ́ńdà wa lórí fíféràn àwọn ènìyàn ní ònà tí Jésù ṣe pé wa? Ìgbà melo ní a tí pa àwọn tó seyebíye sí Kristi tí nítorí a we oréfèé pinnu owórírí won? Àsìkò náà nídí èro tó n gbowó tó sì ń sanwó ní Mo ní ibi tó yẹ kín wá àti pé ẹnìkan tí mọ fé lọ wú lórí. Obìnrin kò jé ẹnikẹni sí mi, nípa ìmọ tara ení nìkan mo nímọ̀lára pé Mi kò ní àkókò láti fí fún un. Àmó Kristi kìí ń pé wa láti sìn Òun nígbà tó bá rórùn fún wa nìkan. Kò béèrè lówó wa láti sìn àwọn tí a rò pé o ye fún afíyèsí wa nikan. Ọ́ máa rànmù àwọn ohun tó ṣe pàtàkì jù lọ sókè sódò—lati obìnrin oníjo sí èyí tó ṣe àwòrán ìhòòhò, tàbí bárakú sí eléré ìdárayá —àti kéde pé pèlú gbogbo àwọn àko tí kò jinlẹ̀, àkókó yóò jé ìkẹyìn àti ìkẹyìn yóò jé àkókó.

Obìnrin náà tó ń sunkún wa ń tiraka láti sí ọkò rè, àti pé Mo nímọ̀lára pé Mo ń sáré síhà è. O tí se pàtàkì jù lọ fún Mi bí ọkàn mi se kún fún àánú fún un. Ní iríṣi ìyàlẹ́nu rè, Mo pèsè gbólóhùn tó jinlẹ̀ lóòótọ́, “Mo káàánú yin fún ipàdánù yín.” Ojú rè tún rún sí àtipe o sí sunkún bí mo ṣe fa a móra. O paróró léyìn ìséjú o sí dúpẹ lówó mi kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ kí o to gun ọkò rè o sí wakò lọ. Mo yípadà síhà èro tó n gbowó tó sì ń sanwó níbi tí ogunlọ́gọ̀ èèyàn ń ṣiṣẹ pèlú àwon fóònù wón, tí wọn möômó pa mi tì.

Àti Mo sí gbà ipò Mi padà lórí ìlà

Beth Castle
Life.Church Creative Media Team (Spouse)

Ìwé mímọ́

Day 6Day 8

Nípa Ìpèsè yìí

Love Like Jesus

Báwo ni a ṣe lè kọ́ láti gbé bí Jésù tí a kò bá kọ́kọ́ fẹ́ràn bí Ẹ̀? Máa káa lo pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ àti tọkọtaya Life.Church bí wọn ṣe sọ asòtúnsọ àwọn ìrírí àti àwọn ẹsẹ ọ̀rọ̀ Ìwé Mímọ́ tó fi wọn sábẹ́ ìmísì láti gbé àti fẹ́ràn bí Jésù.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọ̀wọ́ lọ sí www.life.church