Fẹ́ràn bí JésùÀpẹrẹ

Love Like Jesus

Ọjọ́ 11 nínú 13

Bí Kristi Ṣe Féràn Ìjọ (Apá 2)

A kan tí ṣe ìgbéyàwó fún ọdún méjì tó kúrú ní aṣálẹ̀ ọjó tó kókó ní ìmọ̀lára é: ìrora gógó ẹ̀gún tó pò lápòjú fún gbogbo àwọn ìmọ̀lára rè mìíràn. Lílekoko rè yóò dín kù láàrín àwọn wákàtí tó tè lé nínú ìjì títa ríro, ìrìíra àti omijé. Bí ọmọ ọdún ogun onítìjú àti kékeré, mo tí ṣèlérí láti féràn obìnrin yìí fún réré àti búburú, àmó mọ rọ pé èyí tó burú jù má wá léyìn òpò ọdún ìgbaradì. Kìí ṣe ohun tó ṣẹlẹ̀ nìyẹn. Ìrora náà tún bèrè sini padà wá. Ní alè, pèlú ọmọ ìkókó a tó mbè ní ìsàlè ìyára, a gbìyànjú láti sopọ ní ònà kànnà tí òpò àwọn tọkọtaya tó tí sègbéyàwó n gbádùn, àmó dípò è ìrora lọ wà. Ìyẹn ní àwọn ojó àkókò èyí tó má ṣe ọdún méta òdá àjọṣe tímọ́tímọ́. O yó wọnú ìyára ibùsùn wa àti fì dùgbẹ̀dùgbẹ̀ lórí ìgbéyàwó wa bí òjìji ìròlè ojó gígùn. A tí já ìse tí a sètò láti mú wa sún mọ́ ara wa pẹ́kípẹ́kí gbà a tí fí da àárín wa rù. Òsé má kọjá àtipe a máa tún gbìyànjú ní ìrètí pé ipò tí yípadà, àmó kò i tí yípadà. Láìpé, a kan síwó ìgbìyànjú rárá. Òpò aṣálẹ̀ a kò èyín ara wa sí ara wa lórí béèdì tí a kojú sí ògiri ọtọtọ. Mo lè gbó tón ránu sọ̀rọ̀ ekún bí o ń ṣe gbìyànjú láti fi ìrora rè pamó, àtipe mọ máa sunkún sínú ìrọ̀rí mi.

Kìí ṣe báyìí ní mo se ronú woyé ìgbéyàwó mi. Àwọn abó oúnjẹ àti àwọn ìlédìí, aṣọ fífọ àti gígé koríko—gbogbo ojú iṣẹ pelemo àti túbò da àárín wa rù. Kò sí àkókò iparapò léyìn àríyànjiyàn. Kò sí òwúrò ojó Sátidé. Kò sí àjọròde tí ìjàkadì náà dáwà lọ́kànrú nípa tí ara àti nípa tí ìmọ̀lára. Mo rò pé mó féràn rè bí Kristi se féràn ìjọ, àmó mi o fi bẹ́ẹ̀ mò ohun tó túmọ sí láti jòwó ara mi sílè fún un. Mo kó ìwònba tí mo mò nípa fíféràn bí Kristi. Mọ ronú gidi gan-an nípa sísíwó. Òpò alè, Mo máa dúró títí di ọ̀gànjọ́ òru léyìn ìgbà tó bá tí wolè lọ láti ké sí Olórun nínú ádùrá. Mọ rí asetúnse ìgbìyànjú mi láti tún tètè sopò pèlú è to fọwọ́ rọ́ o ojó léyìn ojó fún àwọn ìdí tí mí kò lóyè è.

Nígbà náà ní Olórun sí àwọn ojú mi, àtipe mọ rántí pé mó ronú, báyìí ni Jésù ṣe nímọ̀lára nípa mi. Ní ararò O ń fé sopò pèlú mi, àmó mọ wà lénu iṣé. Ní alalẹ̀ kí ń tó sún, dípò lilọ àkókò pèlú Jésù, Mọ n lọ owóníná tí ìmọ̀lára mi ti ń yíràá nínú ikàáànùu ará ẹni. Mo lè fojú inú wò ìrora Jésù' àti ìrora ọkàn bí Mo ṣe ko àti tún ko àwọn ìpèwa Rè tó se tímótímó jù lo sílè.

Ní gbogbo ìgbà yìí, mọ n tí di ètó mi mú gégé bí ọkọ nígbà tí mo n so pé o jé nípa mímú ìgbéyàwó lókun sí. Ti mọ bá máa yanjú ìṣòro náà, mo ni látí yípadà. Kódà tó bá dá bí pón segbé kan, mo ni látí paá ètó mi bí ọkọ tí kín sí féràn rè láìkù síbì kan. Torí náà, gbogbo ìgbà tí mo bá nímọ̀lára ọró ìkosílè, Mo máa rántí bí Olórun se nímọ̀lára nígbà tí Mo ko O sílè. Ní Éfésù, o so wipe ọkùnrin tó féràn ìyàwó rè féràn ara rè. Mo kó pé nígbà tí mo nímọ̀lára ẹni tí wọn fẹràn jù lọ, nígbà yeni ni mo ní látí féràn ìyàwó mi. Irú ìdàgbàdénú yìí kò kàn wá pèlú àkókò tón kọjá m. O ní látí mú dàgbà nípasẹ ìrora, ìyòǹda, àti ìrèle.

Síbè mi kò tí dára gan ní fi féràn rè bí Jésù n se ṣe, àmó O tí fí oore ọ̀fẹ́ rà ìgbéyàwó wa padà àti fún wa ní ìdí tó fìdí múlẹ̀. Nítorí ìrora wa àti yíyan wa láti féràn ara wa kọjá rè, a gbádùn ìpele àjọṣe tímọ́tímọ́ tí àwọn ìgbéyàwó mìíràn kò ní ní ìrírí láé.

Michael Martin
YouVersion Team

Ìwé mímọ́

Day 10Day 12

Nípa Ìpèsè yìí

Love Like Jesus

Báwo ni a ṣe lè kọ́ láti gbé bí Jésù tí a kò bá kọ́kọ́ fẹ́ràn bí Ẹ̀? Máa káa lo pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ àti tọkọtaya Life.Church bí wọn ṣe sọ asòtúnsọ àwọn ìrírí àti àwọn ẹsẹ ọ̀rọ̀ Ìwé Mímọ́ tó fi wọn sábẹ́ ìmísì láti gbé àti fẹ́ràn bí Jésù.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọ̀wọ́ lọ sí www.life.church