Fẹ́ràn bí JésùÀpẹrẹ

Fífẹ́ràn Àwọn Ìròbìnújẹ́
A tọ́ mi ilé ti ó túká. Oògùn olóró, otí, àti lílù ni ní àlùbami wọ́pọ̀ àti ohun tẹ́nì ń retí. Kò pé púpò kí ń to mú lára àwọn irú ìwà kan náà ti mo rí lọ́jọ́ojúmọ́. Kí ń tọ mò,mo ń tí mutí òde lále, àti jíjí àwọn ohun tí okọ mọ́mì mi fi pa mọ́ tà fi gbowó àti sábà máa ń lo won. Mo rántí rìnrìn lo sílé ni at 7:00 ni òwúrò kan láti múra fún ilé ìwé lẹ́yìn night of ọtí mímú àti oògùn olóró lílọ. Mo wo ara mi nínú dígí, láìsí ìdùnnú fún ẹnì tó ń wo mi padà.Mo ti di ènìyàn tí mo kórírà fún ìgbà pípé —irú ẹnì tí mo ṣèlérí fún ara mi pé mi kò ni jẹ́ láé. Kò pé púpò fún mi láti dá a láre àti dára mi lójú pé èyí ni a yàn mo mi láti jé. "Ìyẹn ni gbogbo ohun tí ìlú gbígbé kékeré kan lè pèsè,” Mo sọ fún ara mi. "Kí ló tún kù láti se?"
Láàárín àkókò kan náà, Ìyá àgbà mi tẹra mọ́ ìkésími. Ní àwọn òpin ọ̀sẹ̀ kan má juwọ́ sílẹ̀ àti rí pé ara mi balẹ̀ tó tàbí mi kò se ayẹyẹ gidi gan lálẹ́ ọjọ́ tó ṣáájú ọjọ́ náà. Bí mo se sọ tẹ́lẹ̀, Mo gbé ní ìlú kékeré kan. Tí o bá ti gbé nínú oókan ri, o mọ̀ pé gbogbo èèyàn ló sábà máa ń mò nǹkan ti o se kódà kí o to se. O mò nípa oògùn olóró mi ni lílọ àti pé o ti ń gbàdúrà sí Ọlọ́run pé kí Wọn fi ìfẹ́ Rè hàn mi àti àwọn ètò tí Won ni sí mi. Wọn tún je ohun ìlérí àti je ohun ìrètí jù bí mo lè I tiẹ̀ lálàá tàbí rò gbèrò lo.
Ayé nílé ń burú sí i, àti ifífìyà to je ìwọ̀ntúnwọ̀nsì ti wa tibburú jáì. Wiwo eyín wò, o. Jẹ́ ìyàlẹ́nu láti rí bí Ọlọ́run ṣètò ìlà àkókò fún àwọn ìṣẹ̀lẹ̀. Ìfẹ́ ìyá àgbà si mi àti ipá rẹ̀ látigbójú fo àṣìṣe mi dárí mi lo si ebí tó ṣe tán láti gbà mi bí títi won. Wọn wewu lórí òdọ́ tó K kó sí ìṣòro. Nípasẹ̀ ìfẹ́ àti ìtẹ́wọ́gbà won, o ṣeé ṣe fún Mi láti rí ìfẹ́ Kristi fún mi. O jé nítorí ìfẹ́ náà ni Mo fi jẹ ọkùnrin to yí padà. Ọkùnrin pẹ̀lú ìgbéyàwó àti àwọn ọmọ àgbàyanu tí a máa tó ní mimò pé ìfẹ́ tí èmi kò mò nípa tẹ́lẹ̀. Mo Jèrè gbogbo èyí nítorí àwọn ènìyàn bí mélòó kan tó ṣeé ṣe fún láti fẹ́ràn bí Jésù.
Danny Duran
Life.Church Overland Park
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí

Báwo ni a ṣe lè kọ́ láti gbé bí Jésù tí a kò bá kọ́kọ́ fẹ́ràn bí Ẹ̀? Máa káa lo pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ àti tọkọtaya Life.Church bí wọn ṣe sọ asòtúnsọ àwọn ìrírí àti àwọn ẹsẹ ọ̀rọ̀ Ìwé Mímọ́ tó fi wọn sábẹ́ ìmísì láti gbé àti fẹ́ràn bí Jésù.
More