Fẹ́ràn bí JésùÀpẹrẹ

Love Like Jesus

Ọjọ́ 5 nínú 13

Jésù Níbikíbi

Ó jé ìgbà ìrúwé ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kan tí ooru mú nígbà tí ebí mi àti èmi wá sípàdé eré àṣedárayá bọ́ọ̀lù gbígbá ní a yunifásítì kan tó wà lágbègbè wá. Omo nobìnrin tó jẹ́ ọmọdún márùn-ún, àti pé láì tí a dé ìpàdé náà, o kíyè sí ọmọ kékeré ọkùnrin kan tó ń bá ara rè ṣeré. Ọmọbìnrin yẹn kò mò ó. Kò lè sọ èdè Gẹ̀ẹ́sì àti pé o yàtò si ọmọbìnrin yen ni òpò ọ̀nà, àmọ́ kò sí èyíkéyìí tó díi lọ́wọ́ láti rẹ̀rín sí àti dara pò mo eré àṣedárayá tó ń se. Wọn lọ ìrólé papò tí ń wọn rẹ rìn àti wọn si bá ara won ṣeré papọ̀, ní ìparí eré-ìdárayá náà, won jókòó sọ́rí ara wọn mí hẹlẹhẹlẹ im pẹ̀lú ayò ó rè tẹnu tẹnu, wọn fèyìn tí ara won fún ìsinmi.

Nígbà tí wọn ṣeré, èmi àti ọkọ mi padà àwọn òbí rè a sí dárúkọ ara wa fún won. Ìyẹn bẹ̀rẹ̀ àjọṣe tó Sárà ọ̀tọ̀ pẹ̀lú ẹbí tó rẹwà yìí láti orílè èdè mìíràn, àṣà, àti ìgbàgbọ́. Ó fún wa ní àǹfààní láti pé wọn wá sínú ayé wa m, àti ó ní ipá tó jínlè lórí wa. Èyí jẹ́ àǹfààní tó sára ọ̀tọ̀ fún wa láti ṣàjọpín ìfẹ́ Ọlọ́run ní ọ̀nà onídán àti àwọn ọ̀nà tí wa, àti pé ó tèsíwájú láti jé àjọṣe pàtàkì fún ẹbí wá. O na wa, àti ó yí wa padà fún dáadáa.

bẹ̀rẹ̀ nítorí ọmọ wa obìnrin fẹ́ràn ọmọkùnrin kékeré náà bí Jésù ṣe fẹ́. Kìí fi fifẹ́ràn jù lọ hàn. Ó gbà wá bí a ṣe jẹ́, láìka ìgbésí ayé mi àtẹ̀yìn wá wa, àti lọ́wọ́ nínú ayé wa bí jẹ́ Kó wọlé.

Ìgbà wo ni mọ̀ọ́mọ̀ kàn sí ẹnìkan tó yàtò ṣí ẹ kẹ́yìn? Tó bá ti ṣe díè, béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run láti sí ojú rè sí àǹfààní rè tó kàn. Àtipe nígbà tí Ó Ó bà ṣe, gbàrà di láti dáhùn. Ó kàn lè yí ayé è padà.

Amanda Sims
Life.Church Church Online

Day 4Day 6

Nípa Ìpèsè yìí

Love Like Jesus

Báwo ni a ṣe lè kọ́ láti gbé bí Jésù tí a kò bá kọ́kọ́ fẹ́ràn bí Ẹ̀? Máa káa lo pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ àti tọkọtaya Life.Church bí wọn ṣe sọ asòtúnsọ àwọn ìrírí àti àwọn ẹsẹ ọ̀rọ̀ Ìwé Mímọ́ tó fi wọn sábẹ́ ìmísì láti gbé àti fẹ́ràn bí Jésù.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọ̀wọ́ lọ sí www.life.church