Fẹ́ràn bí JésùÀpẹrẹ

Love Like Jesus

Ọjọ́ 6 nínú 13

Fífẹ́ Rán Ẹnì Tí Kò See Fẹ́ràn

Ní ìbámu pẹ̀lú àwọn ìlànà ṣọ́ọ̀ṣì, Mo se dáadáa. Mo “fẹ́ràn elésè, kórìíra ẹ̀ṣẹ̀, ” títí di ọjọ́ tí mo ní láti fi òrọ̀ àsọtúnsọ látìgbàdégbà sílò. Òun nìyẹn níbè, a so ayé mi sínú ẹ̀dùn ọkàn ńláǹlà lórí nítorí ìwà ọ̀dàlẹ̀ tọ́ jínlè.Mo ni láti se yíyàn kan: fi àjọṣe náà sílè tàbí fẹ́ràn èèyàn ti kò ní tí se aíbìkítà nípa ìrora tí a fìje mi, láìsí ikábàámọ̀ tàbí fojú gán-ánní ìpinnu.

Mo wà Ọlọ́run gidi gan fún ọgbọ́n. Kí ni kí n se? Inú àkókò yìí ni Ọlọ́run fi nǹkan hàn mi —ọkàn ọ̀dàlẹ̀ mi. Ọ̀rọ̀ náà “àwọn tí wọn pa lára pa àwọn mìíràn lára” jẹ́ ohun tó ń ṣẹlẹ̀ gangan. Ẹnì yìí aìfararò. O dunni pé, kò mò bí o se máa kọjú e tàbí ibi tó má mú lo, nítorí náà o mú wa sọ́dọ̀ mi.

Ohun tó ń pani lẹ́rìn-ín máa ṣẹlẹ̀ nígbà tí a bá bẹ̀rẹ̀ sí ni fi àkíyèsí lórí àwọn ọkàn àwọn mìíràn dípò ìhùwàsí wọn. A di oníyọ̀ọ́nú—bíi Jésù. Lójijì, kìí se nípa mi mo àti bí mo ti palára. Kàkà bẹ́ẹ̀, o di nípa àwọn ọ̀nà láti fẹ́ràn wọn kọjá ìrora wọn.

Mo gbàgbó pé ohun tí Jésù ń so nìyí ni Rè tó lágbára Ìwàásù lórí Òkè. O máa rọrùn o láti fẹ́ràn àwọn ènìyàn tó ni inú réré sí wa. Kódà àwọn aláìgbàgbó ń se bẹ́ẹ̀. O ṣeé se pé, wón kìí se àwọn tó nílò ìfẹ́ náà jù lo. Láìṣàbòsí, o ṣeé ṣe kó jẹ́ alábàáṣiṣẹ́ tí ń gúni lẹ́yìn, ọkọ tàbí aya tí ń pàro, ọ̀dọ́langba tó ń hùwà ọ̀tẹ̀, tàbí agbawó oúnjẹ tó burú jáì nílé oúnjẹ. Rìnrìn ìrìn àjò fi féràn bíi Jésù ń yí ayé ẹnì padà. Ìfẹ́ ni ń se pẹ̀lú ayérayé lọ́kàn. O jé ewu, àmọ́ oókan tó yé ti ẹnì lè ṣe!

Shannon Morrison
Life.Church South Oklahoma City

Ìwé mímọ́

Day 5Day 7

Nípa Ìpèsè yìí

Love Like Jesus

Báwo ni a ṣe lè kọ́ láti gbé bí Jésù tí a kò bá kọ́kọ́ fẹ́ràn bí Ẹ̀? Máa káa lo pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ àti tọkọtaya Life.Church bí wọn ṣe sọ asòtúnsọ àwọn ìrírí àti àwọn ẹsẹ ọ̀rọ̀ Ìwé Mímọ́ tó fi wọn sábẹ́ ìmísì láti gbé àti fẹ́ràn bí Jésù.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọ̀wọ́ lọ sí www.life.church