Fẹ́ràn bí JésùÀpẹrẹ

Love Like Jesus

Ọjọ́ 10 nínú 13

Bí i Kristi Se Fẹ́ràn Ìjọ (apá kínní 1)

Gẹ́gẹ́ bí ọmọdébìnrin kékeré kan, mo lá àlá nípa ìgbéyàwó mi—láti àkàrà, si aṣọ, àti kódà ọkùnrin náà tí èmi yóò ṣègbéyàwó pẹ̀lú. Nígbà tí ó ń bá lá àlá nípa bí ọjọ́ rẹ̀ tó sárà ọ̀tọ̀ yóò jẹ́, o kò ronú láé nípa bí àwọn àdánwò to máa wá lèyín ọjọ́ náà.

Kí a tó bí mi, àwọn dókítà fàyèwò hàn ìyá mi ni àìsàn oríkèé ara ríro tó lékenkà. Gbogbo ọjọ́ lọ n fi ń jẹ̀rora. Bàbá mi yàn láti fẹ́ràn àti sìn lọ́jojumọ́. Ní àwọn ọjọ́ kankan jẹ́ láti kan pèsè oúnjẹ lóròòwúrọ̀ rè tàbí ràn lọ́wọ́ láti so okùn bàtà rẹ̀. Láìka isé yìí, Bàbá mi fẹ́ràn ìyá mi. Òpò ọdún lẹ́yìn náà, mo rí bàbá mi tí ń sin màmá mi ni ònà títún nígbà tí àwọn dókítà fi àyèwò hàn pé ìyá mi ni àrùn kan tí wọ́n ń pè ní Hodgkin. Bàbá mi lo ọjọ́ rè láti fẹ́ràn, sìn, àti gbàdúrà fún un. Mi kò i tí rí bàbá rẹ̀ tẹnutẹnu nípa ti ara àti èmí, àmọ́ o tẹ̀ síwájú. Èyí sí tún jé his ìfara ẹni sílè rẹ̀ ṣí Kristi bákan náà sí ìyá mi.

Láìpé lẹ́yìn ìgbà tí èmi àti ọkọ ṣègbéyàwó, a dójú ko àdánwò àjọṣe tímọ́tímọ́ tí kò yé kí ìgbéyàwó dójú ko. Isé ṣíṣe tó ń mú ìdùnnú fún wa nígbà kan wa di ohun tó mú ìrora àti omijé wa. Nígbà gbogbo,máa sunkún títí tí oorun á fi gbé mi lọ.. Ìrora náà, àìsí ìbálòpọ̀ takọtabo, àti ìmọ̀lára pé mo jẹ ẹnì kùnà bí ìyàwó mi ṣe da ìdènà sí sáàárín wa.

Àwọn èyí jẹ́ ọjọ́ tó le kọ́kọ́ to yí padà di ọdún tó jẹ́ pé kò sí èyí nínú wa tó ni ìdánilójú pé yóò parí láé. Ọkọ mi dúró dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ mi. O fi gbogbo ìmọ̀lára ìrora lélẹ̀ sẹ́gbẹ̀ẹ́ kan àti yàn láti fẹ́ràn mi níbi tí mo wa. O fẹ́ràn mi kọjá ìrora àti omijé. Lónìí, o yìí fẹ́ràn mi. Àwọn ènìyàn so wi pé say àwọn obìnrin ń wa ọkọ tó tọ́ display irú ànímọ́ rere kan náà gẹ́gẹ́ bí àwọn bàbá won. Lónìí ju ti ìgbàkígbà rí lo, Mo kún fún ọpé pé mo rí a enì kejì bí ọkàn mi tó fẹ́ràn bí bàbá mi àti tó fẹ́ràn bí Jésù.

Shelley Martin
Life.Church IT Team

Ìwé mímọ́

Day 9Day 11

Nípa Ìpèsè yìí

Love Like Jesus

Báwo ni a ṣe lè kọ́ láti gbé bí Jésù tí a kò bá kọ́kọ́ fẹ́ràn bí Ẹ̀? Máa káa lo pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ àti tọkọtaya Life.Church bí wọn ṣe sọ asòtúnsọ àwọn ìrírí àti àwọn ẹsẹ ọ̀rọ̀ Ìwé Mímọ́ tó fi wọn sábẹ́ ìmísì láti gbé àti fẹ́ràn bí Jésù.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọ̀wọ́ lọ sí www.life.church