Àmì-ìdánimọ̀ YouVersion
BíbélìÀwon ètòÀwon Fídíò
Gba ohun èlò náà
Àṣàyàn Èdè
Ṣe Àwárí

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní

15 Oṣù Agẹmọ 2025

Johanu 20:21 - Nítorí náà, Jesu sì tún wí fún wọn pé, “Àlàáfíà fún yín: gẹ́gẹ́ bí Baba ti rán mi, bẹ́ẹ̀ ni èmi sì rán yín.”
Pín
Nítorí náà, Jesu sì tún wí fún wọn pé, “Àlàáfíà fún yín: gẹ́gẹ́ bí Baba ti rán mi, bẹ́ẹ̀ ni èmi sì rán yín.”

Johanu 20:21 (YCB)

Kà Johanu 20:21
Fọwọ́ síi

Àwọn ẹsẹ Bíbélì tó wà fún ọ̀sẹ̀ yìí

14 Oṣù Agẹmọ 2025

“Ẹnikẹ́ni tí ó bá sá à ti pe orúkọ Olúwa ni a ó gbàlà.”

Romu 10:13 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 14 Oṣù Agẹmọ 2025 - àwòrán 0

13 Oṣù Agẹmọ 2025

Ọlọ́run sì wí pé, “Jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ kí ó wà,” ìmọ́lẹ̀ sì wà.

Gẹnẹsisi 1:3 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 13 Oṣù Agẹmọ 2025 - àwòrán 1

12 Oṣù Agẹmọ 2025

Ẹ fi ọpẹ́ fún OLúWA, ké pe orúkọ rẹ̀: Jẹ́ kí a mọ ohun tí ó ṣe láàrín àwọn orílẹ̀-èdè

Saamu 105:1 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 12 Oṣù Agẹmọ 2025 - àwòrán 2

11 Oṣù Agẹmọ 2025

Jẹ́ kí òtítọ́ sàn bí odò àti òdodo bí ìsun tí kò lé è gbẹ!

Amosi 5:24 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 11 Oṣù Agẹmọ 2025 - àwòrán 3

10 Oṣù Agẹmọ 2025

Kí ẹ mọ èyí, ẹ̀yin ará mi olùfẹ́; jẹ́ kí olúkúlùkù ènìyàn kí ó máa yára láti gbọ́, kí ó lọ́ra láti fọhùn, kí ó si lọ́ra láti bínú

Jakọbu 1:19 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 10 Oṣù Agẹmọ 2025 - àwòrán 4

9 Oṣù Agẹmọ 2025

Torí náà, mo wí fún yín ohunkóhun tí ẹ bá béèrè fún nínú àdúrà, ẹ ní ìgbàgbọ́ pé, ó tí tẹ̀ yín lọ́wọ́, yóò sì jẹ́ tiyín.

Marku 11:24 (YCB)

Bible verse of the Ọjọ - ọjọ 9 Oṣù Agẹmọ 2025 - àwòrán 5
Ṣe Ìgbàsílẹ̀ Ohun Èlò náà

Gba Bíbélì ọ̀fẹ́ ti orí ayélujára fún fóònù àti tábúlẹ̀tì.

Gbá ohun èlò ti Bíbélì ìsisìyíwàyí
YouVersion

Ńgbà ọ́ níyànjú ó ṣì ń pè ọ́ níjà láti súnmọ́ Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Iṣẹ́ Ìránṣẹ́

Nípaa

Àwọn iṣẹ́

Oluyọọda

Blọ́ọ̀gì

Tè

Àwọn ojú-ìwé tí ó wúlò

Ìrànlọ́wọ́

Fifún ni

Àwon Èyà Bíbélì

Àwọn Bíbélì àfetígbọ́

Àwọn Èdè Bíbélì

Ẹsẹ̀ Bíbélì t'Òní


Isẹ́ Ìránṣẹ́ orí ẹ̀rọ ìgbàlódé

Life.Church
English (US)

©2025 Life.Church / YouVersion

Ìṣe ìdá kọ́ńkó̩Àwon àdéhùn
Ètò Ìpolongo Àwọn Àìléwu
FacebookTwitterInstagramYouTubePinterest

Ilé

Bíbélì

Àwon ètò

Àwon Fídíò