Fẹ́ràn bí JésùÀpẹrẹ

Love Like Jesus

Ọjọ́ 9 nínú 13

Ara Kan, Ibi Ara Púpò

Mo se parí ọ̀rọ̀ lórí fóònù pẹ̀lú àwọn òbí mi tí wọn sọ ìròyìn tí mi kò ro tàbí retí pé máa gbó fún mi— arákùnrin mi tí gba èmí ara rẹ̀. Mi o mò ohun tí máa se nítorí o jé ẹnì tí ń mo sá ba ní àkókò àìní. Nígbàkigbà tí ohunkóhun bá ṣẹlẹ̀, dára tàbí búburú, òun ni enì àkọ́kọ́ tí mo máa pé.

O seẹnu rẹ, Mo ni àwùjọ of àwọn ènìyàn láti sáyé pẹ̀lú. Mo pé adarí ẹgbẹ́ mi kékeré, àti láàrín wákàtí kan, àwọn ọ̀rẹ́ mẹ́rin wá sí ilé mi láti wà pẹ̀lú mi. Àti pé ohun tó ṣẹlẹ̀ lórí àwọn ọ̀sẹ̀ àti oṣù tó ń mbò jẹ́ ohun tó ṣòroó gbà gbọ́. Àwọn kan wá sọ́dọ̀ mi láti jẹ kín ké. Àwọn mìíràn gbé mi jáde àti mú mi rẹ́rìn-ín. Àwọn mìíràn pèsè oúnjẹ. Àwọn mìíràn se itọrẹ àánú ní ọlá arákùnrin mi. Àwọn mìíràn wakọ̀ ni òru láti wà ní ìsìnkú arákùnrin mi láti sá tí lẹhin fún mi. Mìíràn tún se ilé mi lọ́ṣọ̀ọ́ nígbà Kérésìmesì láti to kí mi káàbọ̀ padà láti àjò mi tó le. Àwọn ọ̀rẹ́ mi se ohun tí Ọlọ́run mú oókan kan lára won gbára dì láti se láti tojú bìkítà fún mi.

Kọ́ríńtì Kíni 12 kọ́ pé a jẹ́ ara kan pẹ̀lú òpò apá. Ọlọ́run ti fún oókan kan lára wa ni àwọn ẹ̀bùn aláìlẹ́gbẹ́, àwọn tálẹ́ńtì, àti ìfẹ́ onígbòónára láti lo láti sìn àwọn mìíràn. Mo kún fún ọpé títí láé fún àwọn ọ̀rẹ́ mi tó ń lo ohun ti won ni láti sìn mi ni ìgbà ìbànújẹ́ mi. Lónìí Mo fé fún yín níṣìírí láti rántí pé o ní ohun to gbà gan-an láti sìn àwọn mìíràn àti fẹ́ràn bí Jésù ni àkókò of àìní ńlá.

Amanda Davis
Life.Church Tulsa

Ìwé mímọ́

Day 8Day 10

Nípa Ìpèsè yìí

Love Like Jesus

Báwo ni a ṣe lè kọ́ láti gbé bí Jésù tí a kò bá kọ́kọ́ fẹ́ràn bí Ẹ̀? Máa káa lo pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ àti tọkọtaya Life.Church bí wọn ṣe sọ asòtúnsọ àwọn ìrírí àti àwọn ẹsẹ ọ̀rọ̀ Ìwé Mímọ́ tó fi wọn sábẹ́ ìmísì láti gbé àti fẹ́ràn bí Jésù.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọ̀wọ́ lọ sí www.life.church