Àwon Òtá Okàn

Ọjọ́ 5
Gẹ́gẹ́ bíi ọkàn tí ara to méwulọ́wọ́ lè pa ara wa run, ọkàn tọ́ méwulọ́wọ́ nípa tí èrò - ìmọ̀lára àti nípa tẹ́mí lè pá ìwọ àti àwọn àjọṣe rè run. Fún ọjọ́ márùn-ún tó ń mbò, jẹ́ kí Andy Stanley rán ẹ lọ́wọ́ láti wò inú ara rè fún àwọn ọ̀tá ọkàn mẹ́rin tó wọ́pọ̀ — èbi, ìbínú, ojúkòkòrò, àti owú — àti pé kò ẹ bí ó máa ṣe yọ wón kúrò.
A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ Andy Stanley àti Multnomah fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé síwájú síi, jọ̀wọ́ lọ sí:
bit.ly/2gNB92i
Nípa Akéde