Fẹ́ràn bí JésùÀpẹrẹ

Love Like Jesus

Ọjọ́ 4 nínú 13

Ètè Nínú Ìrora

Ọdún bí mélòó kan sẹ́yìn, èmi àti ìyàwó mi rí ara wa lórí ìrìn àjò ẹ̀dùn ọkàn àti ìrora bí a sé tiraka láti bẹ̀rẹ̀ ẹbí wá.Àwọn ọ̀rẹ́ ń ní àkọ́bí won, lẹ́yìn náà abísé kejì ... àti àwa ń yin béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run ìdí tí a kò fi lóyún. Ọdún mẹ́rin lẹ́yìn náà, òótọ́ ni a lè a lè ríi pé ìrìn àjò àìrọ́mobí wa jẹ́ ara ètò ńlá . Ó yí padà di púpọ̀ jù bẹ́ẹ̀ lọ tí a kò lè ronú kàn láé. Àmọ́ kí isé ìyanu tó ṣẹlẹ̀ , ohun tó mú wá kọjá ìrora náà? Ègbéì Ìwàláàyè Wa.

Wọn fẹ́ràn wa bí Jésù àti dara pọ̀ mọ́ wa nínú gbígbé ìrora àti ìjákulè and every day. Wọn fi Orin Dáfídì 34:18 hàn fún wa gidi gan-an . A ní ìrírí ìtùnú Ọlọ́run ni gbogbo ìgbésẹ̀ ojú ọ̀nà bí Ẹ̀mí Mímọ́ ń ṣíṣe nínú Ègbé Ìwàláàyè.

Nítorí àtilẹ́yìn wọn , a sọ nípa ìrìn àjò wá jáde àti pé ó fún wa láàyè láti ṣàjọpín ìhìn réré ìrètí tí Ọlọ́run pẹ̀lú àwọn tọkọtaya mìíràn tó ń rò pé wọn dá nìkan wà nínú ìtiraka yìí. Àmọ́ Ọlọ́run kò kan dúró níbè. Lẹ́yìn ọdún mérin ni gbigbìyànjú láti ni ọmọ , gbìyànjú láti dín ìnáwó kù fún ìmúlóyún lóde ara, ní dídi àwọn alágbàtọ́ tí a fún láṣẹ , àti kí Ọlọ́run tó sí ilẹ̀kùn fún isé túntun ó kù díẹ̀ 16 wákàtí hours láti from ẹbí wa, Ọlọ́run gbó àdúrà wa.

Ní ìṣẹ́jú àáyá kan, gbogbo ohun yàtò. Ìyàwó mi lóyún ! Lẹ́yìn osù mélòó kan, Emma ọmọ ìkòkò wá tó rẹwà wá sínú ayé yìí, àti méfòó lára àwọn èèyàn àkókó tí a sọ fún je ? ÈgbéÌwàláàyè wá. Àwọn ni wọn gbé ẹrù ìnira àti ìrora nígbà tí a kò lè dá nìkan kápá e, àti pé àwọn ni a se àjọyọ̀ pẹ̀lú jù lọ!

Torí náà kini o kojú ẹ lónìí? tí ó bá ní ìmọ̀lára dídá wá, kan mò èyí pé Irọ́ tó jìnnà sóòótọ́ gbáà lèyí jẹ́ nítorí Kristi rìn pẹ̀lú wa ni gbogbo ìgbésẹ̀ ònà àti pẹ̀lú ète fi àwọn ènìyàn sínú ayé wa fún ìdí kan. Èyíkéyìí àkókò ìrora tí a bá ní ìrírí, a kìí se alákókó yálà lọ máa jẹ́ ìgbẹ̀yìn . Àmọ́ a ní olùgbàlà kan tó sún mọ́ ọkàn wa ni àkókò wá tó ṣókùnkùn jù lọ. Níwọ̀n bí a bá ní òtítọ́ yìí láti di mú, a lè àwọn tó máa dárí àwọn ènìyàn sí Ẹnì tó tóbi jù ẹ̀dùn ọkàn wọn lọ, ẹnìkan tó lè gbé wọn kọjá àti kódà mú ète sí ìrora wọn. Orúkọ Rẹ̀ ni Jésù.

Ìrora wá ní èrí wa. Ìtàn wa ti òdodo Ọlọ́run. Àti kọjá ìrora náà, a lè ní ìgbẹ́kẹ̀lé ni Ọlọ́run ní mimò pé Ó fẹ́ràn wá, Ó wà pẹ̀lú wa, àti pé Ó pò jù bẹ́ẹ̀ lọ .

Jay Porter
Life.Church Keller

Day 3Day 5

Nípa Ìpèsè yìí

Love Like Jesus

Báwo ni a ṣe lè kọ́ láti gbé bí Jésù tí a kò bá kọ́kọ́ fẹ́ràn bí Ẹ̀? Máa káa lo pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ àti tọkọtaya Life.Church bí wọn ṣe sọ asòtúnsọ àwọn ìrírí àti àwọn ẹsẹ ọ̀rọ̀ Ìwé Mímọ́ tó fi wọn sábẹ́ ìmísì láti gbé àti fẹ́ràn bí Jésù.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọ̀wọ́ lọ sí www.life.church