Fẹ́ràn bí JésùÀpẹrẹ

Love Like Jesus

Ọjọ́ 3 nínú 13

Iṣẹ́ Àyànfúnni Tí Ọlọ́run

Ọlọ́run mbẹ lórí isé. Èyí dámi lójú gan. Ọlọ́run mbẹ wà láàyè, fara sí, àti ń ṣisé lónìí gẹ́gẹ́ bí O ti wà nígbà ẹgbẹ̀rún ọdún àwọn àkọsílẹ̀ Ìwé Mímọ́. Ní ìbẹ̀rẹ̀, O dá gbogbo ohun ni ipò ìbáradọ́gba tí ìṣọ̀kan, ìrísí, àti ẹwà. Àmọ́ sá o, òténté ìṣẹ̀dá Rè ko ìbálòpọ̀ látọ̀dọ̀ Ọlọ́run sílè. Látìgbà náà, Ọlọ́run tí ń fkọnu ìfẹ́ sí wa padà sọ́dọ̀ Rè. Òun ni ìtàn ìpẹ̀kun ìfẹ́. Ọlọ́run bé sínú adágún tó dì gbagidi nígbà tí a bá ṣubú sínú e. O sáré wọnú ilé tó ń jó nígbà tí a bá kó sínú e. O yó ògiri ọ̀dájú ọkàn wa nígbà tí a bá se ìpínyà àti tún fún ara lókun ni inú ẹrù, ìkórìíra, ìtìjú àti àwọn àìsí ìfọ̀kànbalẹ̀ wa. Àmọ́ apá tó dára jù lo ni, O pé láti dára pò mo Òun lórí iṣẹ́ àyànfúnni tí ìrètí yìí.

A jé ọ̀tá Ọlọ́run nígbà kan, a ń yàn èyíkéyìí ẹyọ àwọn ọlọ́run èké. O fẹ́ràn wa tó jẹ́ pé O rán àti fún jòwó Ọmọ Rẹ̀ kan ṣoṣo. Fún wa. Ọ̀tá Rè. Èyí ni àpẹẹrẹ tí a fi lélẹ̀ fún wa. Ìrètí wa, àti iṣẹ́ iṣẹ́ àyànfúnni tí a pé wa láti dára pò ni láti fẹ́ràn àwọn ọ̀tá wa. Ìyẹn ni ohun ajíhìnrere tí a lè se jù láé. O jù ọ̀rọ̀ lo àti ìṣe lọ. O jé ìgbé ayé tó kópa nínú isé Ọlọ́run. Tí ayé bá rí ìgbòkègbodò àwọn ènìyàn tó ń ni ìkóra-ẹni-níjàánu tó láti má se jà padà, àánú tó pò tó láti wà ìfìmọ̀ṣọ̀kan, àti ìrẹ̀lẹ̀-ọkàn láti rí agbára nínú ààrenígbà náà aráyé yóò mò Kristi ni ìrísí ni ìrísí Rè gangan —ìrísíàgbélébùú.

Joey Armstrong
Life.Church Broken Arrow

Ìwé mímọ́

Day 2Day 4

Nípa Ìpèsè yìí

Love Like Jesus

Báwo ni a ṣe lè kọ́ láti gbé bí Jésù tí a kò bá kọ́kọ́ fẹ́ràn bí Ẹ̀? Máa káa lo pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ àti tọkọtaya Life.Church bí wọn ṣe sọ asòtúnsọ àwọn ìrírí àti àwọn ẹsẹ ọ̀rọ̀ Ìwé Mímọ́ tó fi wọn sábẹ́ ìmísì láti gbé àti fẹ́ràn bí Jésù.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọ̀wọ́ lọ sí www.life.church