Fẹ́ràn bí JésùÀpẹrẹ

Love Like Jesus

Ọjọ́ 2 nínú 13

Ìdáriji Lápapò

Sóòsì ní a tí tó mi, àmó lótítọ, mo gbé bí ẹni pé kò sí Olórun. Nígbà tí àwọn ànfààní wa fún mi láti fífé hàn sí àwọn ẹlòmíràn ní ilé ìwé tàbí ìbí iṣé, mi kò lọ àwọn ànfààní wọnyìí. Mọ jé oni ìwà òmùgọ̀. Mo jé onímọtara-ẹni nìkan àti onígbéraga. Bíbojú wẹ̀yìn, àwọn lájorí ipá tó ṣẹ nínú ayé mí jé búburú: àwọn òré àìtó, àwọn ìbáṣepọ̀ tó sèpalára fún ni, ìbálòpọ̀, àwòrán ìṣekúṣe, àti ọtí mímu. Mo wa já sáàárín ogunlọ́gọ̀ awọn èèyàn àìtó, mọ ń paró fún àwọn òbí mi, mọ ń paró fún àwọn òré mi, mímú ọtí, àti bó ìgbé l'aruge eké ti mo gbèrù. Nígbà tí Mo wà dé ìdajì kọlẹẹjì, Mọ n se àwọn ohun burúkú tón fẹ́rẹ̀ẹ́ fọ́ ara àti ayé mi.

Sáré síwájú sí 2010 òsé díè kí o tó dí odun Àjíǹde. A tí pé ẹbí mi wá sí SóòsìAláàyè. Lákókò yìí, a kò i tí lọ sí sóòsì ní òpò ọdún. O jé àkókò lílekoko nínú ayé mi àti ayé ẹbí mi, àti pé ìpèwa yìí kò bá máa tí iwa nígbà mìíràn tó dára. A wolé ati gbogbo èèyàn kí wa káàbò. O jé nǹkan tí mí kò ní ìrírí rẹ lóòtó láé rìnrìn wọnú Sóòsì. Láàrín ìsìn àkókó tí a lọ, ìfé àti ìdáriji Olórun borí mi lápòjú fún ìgbà àkọ́kọ́ ní ayé mi. Ìhìn isé náà sòrò nípa ìdáriji, àtipe mọ lóyè ìtàn Jésù àti ìfẹ́ Rè. Mi kò dúró. Mọ sepinnu láti jòwó ayé mi fún Kristi ní ojó yen gan-an. Mọ nímọ̀lára pé Olórun fò mi mó láti inú gbogbo àwọn ohun burúkú tí mo tí se, àti pé Mọ jé ẹni tuntun. Kìí ṣe gbogbo yìí nìkan o, bí o tí lè jé pé. Mo rí i pé Mo nílo àtìlẹ́yìn. Mo nílo láti darapọ̀ mo ÈgbéAlààyè, ègbé kékeré kan tí àwọn èèyàn ṣe ayé papó.Mo rí ọ̀dọ́ kan, a ṣe àjọdásílẹ̀ ègbé tá máa ni pàdé lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ ní Ojó ìṣẹgun, àti pé mo bèrè sí ní lọ. Níbí yìí ní gbogbo ohun tí yípadà.

Àwọn òré yìí féràn mi, wón gbà mi, àti òpò gbogbo e, fí ohun tó dá bí láti gbé fún Kristi hàn mi. Mi kò lè gbàgbé bí ègbé àwọn ènìyàn ṣẹ féràn mi bí Jésù máa ṣe féràn mi. Wón gbà mi wolé gégé bí mo sé jé, àti ràn mí lówó láti bórí ayé àtijọ́ mi àti gbá ìgbé ayé titún tí Olórun ní fún mi móra. Mọ nímọ̀lára pé wón gbà mi, àti pé wón kò dá mi léjó nítorí ohun tí mọ tí ṣe. Wọn fífé àti àtìlẹ́yìn tí mọ nílo gidigidi hàn mí desperately ní àsìkò yìí ní ayé mí.Olórun lọ ègbé kékeré yìí tí àwọn ọmọ tón wa láàrín ogun ọdún àti se ìrísí mi sí ení tí mọ jé lónìí. Sáré síwájú di òní, àtipé gan mọ n ṣiṣẹ ní sóòsì kan, lórí ègbé àwùjọ kékeré yìí, àti pé rẹ́ni tẹ́tí gbọ́ ìtàn léyìn ìtàn tí a yípadà nítorí ìfé Kristi. Olórun lè yí ayé è padà, àtipe a àkókò yìi, O máa ṣe nípasẹ̀ àwọn tó yí wa ká..

Day 1Day 3

Nípa Ìpèsè yìí

Love Like Jesus

Báwo ni a ṣe lè kọ́ láti gbé bí Jésù tí a kò bá kọ́kọ́ fẹ́ràn bí Ẹ̀? Máa káa lo pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ àti tọkọtaya Life.Church bí wọn ṣe sọ asòtúnsọ àwọn ìrírí àti àwọn ẹsẹ ọ̀rọ̀ Ìwé Mímọ́ tó fi wọn sábẹ́ ìmísì láti gbé àti fẹ́ràn bí Jésù.

More

A fẹ́ dúpẹ́ lọ́wọ́ ìjọ Life.Church fún ìpèsè ètò yìí. Fún àlàyé díẹ̀ síi, jọ̀wọ́ lọ sí www.life.church