Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Jésù ni “Ọmọ Aládé Àlàáfíà” nítorí nínú Òun nìkan soso ni ènìyàn ni ìfẹ́ Olórun to dára-ati àlàáfíà lori ilè ayé. Àwa ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run, nípasẹ̀ olùfẹ́ ọ̀wọ́n Ọmọ Rè àlàáfíà Olórun to ga le wa si gbogbo ọkàn ati si gbogbo orílẹ̀-èdè lábẹ́ òrun, sùgbọ́n kosi le wá nípasẹ̀ ọ̀nà mìíràn. Kosi oókan lara wa tole ni ìfẹ́- to dára si Olórun ti ako ni tẹ́tí si Ọmọ Rè. Ònà kan soso si àlàáfíà ati ìgbàlà ati agbára, ati lati ni gbogbo ohun ti Olórun ni ni ọ̀nà àdúrà ati àwọn ìbùkún fun ẹnì kọ̀ọ̀kan wa ati fun gbogbo ayé, ni Ọmọ Ènìyàn.
Nígbà tí aba lò àpólà ọ̀rọ̀ “ Ítara Olúwa wa” o tumọ̀ si ìyípadà si àlàáfíà ati agbára ati sùúrù.
Ìbéèrè Ijiroro: Àwon ọ̀nà wo ni mo n gbìyànjú láti ni àlàáfíà pèlú Olórun láìṣi ípasẹ̀ Ọmọ Rè? Nje àlàáfíà mi ni ítara tabi imẹlẹ?
Awọn Àyọlò Òrọ̀ ti a mu lati Òun Yóò Semi Lògo Mi, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org