Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Ọjọ́ 23 nínú 30

Nìgbàti adi atúnbí láti òkè wa, iyára àti ijí díde nipase Olórun a rí wipè o see e láti ṣàyẹ̀wò òdòdó lílì nitori à kò ní àlàáfíà Olórun nìkan, Ṣùgbọ́n àlàáfíà gan-an to se farahàn Jésù Kristi. Àwa jókòó si ibi ọ̀run nínú Kristi Jésù. Ònà atijo ti a nmá gbà sé ohun, awuyewuye ti atijo àti ífìbínú ti ku, a ti di èdá titun nínú Kristi Jésù. Nínú èdá titun yi ni ifarahàn iru àlàáfíà gan-gan ti o farahàn nínú Jésù Kristi.

Nígbà tí Olórun jí wa díde wọnú àwon ibi ọ̀run. Ó Fún wa ní ìmọ́gaara ti Jésù Kristi gangan. Òhun ti ìgbé-ayé ísọ di mímọ́ tumọ̀si niyen—àgbègbè àlàáfíà tí kò ní ìyọlẹ́nu àgbègbè Rè, the ifẹsẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin, agbára ti kìí ṣàárẹ̀ ti okun Rè, àti àwámárìídìí, àgbá ìmọ́gaara ti wiwà ní mímọ́ Rè.

Ìbéèrè Ijiroro: Nje mo ṣiyè méjì ati fífìbínú lórí gbogbo àìfararọ tabi se mo rí pé ó ṣeé ṣe wipé à mu won sibe làti jẹ́ kí lọ́ra díè àti làti mú mi rí òhun tó ṣe pàtàkì timo lè ti pàdánù?

Awọn Àyọlò Òrọ̀ ti a mu Láti Ogún Ìní Wa Tó Mọ́lẹ̀ Yòò © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 22Ọjọ́ 24

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.

More

A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org