Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Àlàáfíà ti Kristi sọ́kàn pèlú é̩dá Rè gan-an, àti iṣẹ́ àlàáfíà sàfihàn ní ìgbé-ayé lórí ilẹ̀ ayé Olúwa wa. Olórun alàlàáfíà ni Enì ton sọ di mímọ́ pátápátá. Èbùn àlàáfíà ti Kristi ní inú; àwùjọ ti Olórun ní òde, nígbà náà mo ní-lò láti rí pé mo fún àlàáfíà ti Olórun láàyè láti lànà gbogbo ohun tin mo nse, èyí ni ibi tí ẹrù iṣẹ́ mi ti jáde —“jẹ́ kí àlàáfíà ti Kristi ṣakoso nínú okàn yin.”
Òkan lara àwon ohun ti a ní-lò láti wo sàn ni ara wa nípase Olórun alàlàáfíà ni ń tiraka rírùn láti se àwon ohun fu ara wa. Nje Olórun alàlàáfíà ti mu o wonú pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́, tabi ariwo àti titiraka síbẹ̀? Sè o rọ̀ mọ́ nñkan ìdánilójú olórí kunkun tìrẹ?—o tiraka pèlú àwon ilà ohun pàtàkì tofẹ́.
Ìbéèrè Ijiroro: Kí ni o tumọ̀si láti fún àlàáfíà láàyè láti ṣakoso okàn wa? Kí ni iyàtọ̀ láàárín wiwà ni pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ àti gbigbé ní àlàáfíà? Kí ni iyàtọ̀ láàárín pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ àti àlàáfíà?
Awọn Àyọlò Òrọ̀ ti a mu Láti Rere Tó Ga Jù Lọ Àti Bí O Bamá Bèrè © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org