Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Ọjọ́ 25 nínú 30

Ọ̀pọ̀ èniyàn won ko rí ohun tí kò jé àìtọ́, àti òrò wòlíì bii Jeremáyà jé òmùgọ̀. A kòle dojúkọ àwon ohun tiwon jè àìtọ́ láé, yàtọ̀ si Olórun, láìdi asínwín. Ti ẹ́ṣẹ̀ bajè ohun tí kò tó nǹkan àtipe a lè wàásù ìwòsàn fun èniyàn àti mú àlàáfíà lori eyikeyii ilà miiran, nígbà náà ìbànújẹ́ ti ori igi àgbélébùú jè àṣìṣe ńlá. Láti gbé ìgbé-ayé ṣàfipamọ́ pèlú Kristi nínú Olórun túmọ̀si a rí nígbà miiran ohun ti àwọn ọkùnrin àti àwọn obìnrin dabii laisi Olórun, láti ojú ìwòye Olórun, àtipe o tun túmọ̀si ki a dọ́gbọ́n bẹ̀bẹ̀ fún ìrànlọ́wọ́ fun wọn, nígbà tí wọn wo wa pèlú àánú.

Bọ́ pátápátá lọ́wọ́ ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀. Fà ìránṣẹ́ Rè sẹhin kúrò ni ẹ́ṣẹ̀ ìkùgbù. Oh fi hàn pé mo lè rí i pé Ó sè àfihàn àlàáfíà àti ìmọ́gaara Rè nínú mi!

Ìbéèrè Ijiroro: Kí nìdí tí a gbọ́dọ̀ yẹra fún ohun àìtọ́ kí a tó mú wa ni ọ̀tún? Kí nìdí tí is it kò ṣeé ṣe làti ni àlàáfíà níbi tí ẹ́ṣẹ̀ wá? Kí nìdí tí ìmọ́gaara pọn dandan fun àlàáfíà?

Awọn Àyọlò Òrọ̀ ti a mu Láti Àkọsílẹ̀ lori Jeremáyà àti Kíkàn Ilẹ̀kùn Olórun, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 24Ọjọ́ 26

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.

More

A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org