Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
A gbọ́dọ̀ dà bí ìyọnu àjàkálẹ̀ ti ẹ̀fọn si Alágbára Ńlá pèlú àwon iráhùn ironú kékeré àti àwon àníyàn, àti àwon ọkàn to dàrú ti a ń là kọja, gbogbo e naa nítorí a kó ni wọnú àwọn ohun ìpìlẹ̀ ayé pèlú Olórun ti Jésù wa làti fún. “ìfẹ́ Rè ni àwon ìgbà toti kọja séyìn”o yẹ ká lè simi nínú Rè. Ààbò wa láti ánàá, àbò fun óla, àti àbò fun òní. Ìmọ̀ yi lo fun Olúwa wa ni àlàáfíà to parọrọ To n ni nìgbà gbogbo.
Àwùjọ je igbìyànjú ènìyàn láti kó ìlú Olórun; ènìyàn ni ìdánilójú pé bí Olórun bá fun oun ni àsìkò tó pò tó oun yoo kó konkinse ìlú mímó nìkan soso, sùgbón àwùjọ mímó àti láti fi ìdí àlàáfíà múlẹ̀ lori ayè, àtipe Olórun ti fún n ni àyè áti àǹfààní púpò láti gbìyànjú, títí ó fi ni itẹ́lọ́rùn wipé ònà Olórun nìkan ni ònà.
Ìbéèrè Ijiroro: Àwon idààmú àti àníyàn wo ni mo n ṣe lọwọ ninu eyiti to sàfihàn aini àlàáfíà mi? Àwon àwùjọ àti ìlànà ètò wo ni a kọ́ to fojú kérétán iní-lò wa fún àlàáfíà pèlú Olórun?
Àwon Àyọlò Òrọ̀ Ti A Mu Làti Ìlànà Ìwà Híhù Ti Bíbélì Àti Rere To Ga Jù, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org