Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú Olúwa
Ọjọ́ 30
Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.
A fé láti dúpé lówó Akéde Discovery House Publishers fún pipèsè ètòbyìí. Fún ìsọfúnni sí i, E jòó ṣèbẹ̀wò: www.utmost.org
Nípa Akéde