Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Ọjọ́ 1 nínú 30

Ìdúnnú túmọ̀ sí ìjẹ́pípé ìmúṣẹ fún èyí tí à sèdá mi fún àti ìsdọ̀tun, kì í se àṣeyọrí ní sise ohùn kan. Ìdúnnú Olúwa wá tó sùn ni sise ohun ti Bàbá ràn láti se. Gbogbo wá ní láti rí àyè wá nínú ayé àtipe ní tèmí à rí i nígbà tí à gbà iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa láti òdò Olúwa. Kí a baà lè se èyí a gbódò ti rìn pèlú Jésù; à gbódò mò Ó jù gégé bí Olùgbàlà tí ara ènì nìkan lo. Se mo gbá iṣẹ́ òjíṣẹ́ láti òdò Olúwa? Tí o bá rí bée, mo ní láti jé adúróṣinṣin, láti kà ayé mi ni ìyebíye gidigidi nìkan fún ìmúṣẹ iṣẹ́ òjíṣẹ́ yen.

Olúwa, sí Ó ní mo wa. Fún mi ní óore ọ̀fẹ́ ti ń wọlé fún tí ayé Rè títí ìrònú mi, inú òye mi, àti ọ̀rọ̀ sísọ mi máa fi jé gbogbo È. Bí È ti sọ èmí mi dọ̀tun lona titóbilọ́lá àti mú mi padà bọ̀ sípò sí ìdùnnú ìgbàlà Yín!

Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Kí ni àyè tèmí mi? Kí ni mo n se tó jé pé emí nìkan lolè se? Kí ni iṣẹ́ òjíṣẹ́ mi láti ọ̀dọ̀ Olúwa? Se mo jẹ́ adúróṣinṣin sí i? Ní ònà wo ní ayé mi ṣeyebíye gidigidi sí Jésù?

À mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Ipè é níti Olórun àti kíkàn ìlẹ̀kùn Olórun © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.

More

We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org