Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Ọjọ́ 5 nínú 30

Ònà kan soso tí a lè gba gbádùn “igi ìyè” wa ni nípa ìmúṣẹ ìdí tí à fi sèdá wa. Jésù Kristi gbàdúrà “pé kí wón ní irú ìdùnnú Mi ni ìmúṣẹ nínú ara wón.” Ohun tó mú Jésù ní ìdùnnú kì í se pé Ó ta kété sáwọn ohun gangan, sùgbón pé Ó ní ìjọba nínú. Gbogbo ìgbésí ayé Olúwa wa pátá ní gbòǹgbò àti tẹ́jú nínú Olórun, Kò sàárẹ̀ láé tàbí jé alainigbẹ́kẹ̀lé.

láàárín ààlà ìbímo àti ikú mo lè se bí mo se fé; sùgbón mí ò lè so ara mi dí ọmọ tí à kò tíì bí, kò sì mi kò lè bọ́ lọ́wọ́ ikú, àwon ààlà méjeéjì wà níbẹ̀. Mi ó ní ohunkóhun láti se pèlú fifi àwon ààlà, sùgbón láàárín wón mo lè yorí sí ohun ti ìtẹ̀sí-ọkàn mi yàn. Bóyá mo ní àkókó ìdààmú tàbí àkókó ìdùnnú sinmi lórí ohun tí mo se láàárín ààlà ìgbà náá.

Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Àwon èèyàn wo ní mo fún láàyè tó mú mi di alainigbẹ́kẹ̀lé? Kí nìdí tí mo fí fún ìlànà wón àti ìpinnu wón láàyè láti dín ìdùnnú mi kù? Nígbà tí mo bá fún ẹ̀mí alainigbẹ́kẹ̀lé láàyè, Kí ló so fún mi nípa ìlànà tèmi? Àwon ìpinnu wo lo lè mú mi láti ṣàfirọ́pò ainigbẹ́kẹ̀lé pèlú ìdùnnú?

À mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Si gá síbẹ̀ fún Ènì tó ga jùlọ àti Òṣìṣẹ́ Olórun © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 4Ọjọ́ 6

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.

More

We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org