Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Ọjọ́ 9 nínú 30

Ìwé Mímọ́ kún fún ọ̀rọ̀ ìṣílétí láti yọ̀ gidigidi, láti yìn Olórun, láti kọrin sókè ketekete fún ìdùnnú; àmó ígbà tí ènìyàn ba ní ìdí láti yọ̀ gidigidi, láti yìn, àti láti korin sókè ketekete nìkan ní àwon ohun yi lè sée se nítòótọ́ láti inú òkàn. Nínú àkóso ara ìpíndọ́gba okùnrin alàìsàn kò gbá ìwòye alárinrin gan tí ayé, àtipe pèlú okàn alàìsàn alárinrin tòótó àti ọ́yàyà jé ohun ti kò ṣeé ṣe fún u. Àyàfí ti okàn bá ti wò sàn nigbagbogbo ní afoniláyà tó fara sin wá àti èrú tó ji ọ́yàyà kúrò àti ìdùnnú aláìṣeéfẹnusọ tí o jé ìfẹ́ ọkàn Olórun fún gbogbo àwon omo Rè.

Ígbà tí Olórun ba mú ayé le owó ní ìdáǹdè látowó ìrẹ̀wẹ̀sì lè wá. Gbigbé nínú àlàáfíà àti ìdùnnú ti ìdáríjì Olórun àti ojúurere ní ohun kan soso tó máa mú ọ́yàyà wa.

Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Kì ni ìdí fún yiyọ̀ gidigidi? Láti inú àìsàn wo—ti ara tàbí ti èmí—se à tí wò mi sàn? Láti inú ìrẹ̀wẹ̀sì wo ní mo ti gba ìdáǹdè? Láti inú èrù wo ní à ti dá mi silẹ lominira?

À mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Àwon Òṣìṣẹ́ Olórun © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 8Ọjọ́ 10

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.

More

We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org