Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Ọjọ́ 13 nínú 30

Sólómọ́nì ni gbogbo ohun tí okùnrin lè ni ní ayé, ó ni gbogbo ọnà láti tẹ́ àra rè lórùn; ó gbìyànjú ilà oníwà ẹranko, ilà gigalọ́lá, ilà àtọwọ́dá, ilà amòye sùgbón, ó sówipe, ó kò lè rí ìdùnnú rè tó pépé títí nínú àwon èyíkéyìí wón. Rírí Ìdùnnú wa láti ínú ìbáṣepò rè sí Olórun nìkan nígbà tón gbé lori Ilẹ̀-ayé yìí, Ilẹ̀-ayé ti o ti wa àti Ilẹ̀-ayé tí o n padà si. Èrùpe ní ìdá-ìpìlẹ̀ tó dára jù ní ènìyàn, nítorí nínú è ní ògo Olórun ni láti ni ifàrahàn.

Ohun ti Olórun sèdá ní ìsọdimímọ́ si Olórun, sùgbón títí à o fi mo Ó kò si ìsapá ńláǹlà ní ìṣèdá Rè tí à n gún èjìká wa si. Tí a bá ṣáà lòye Olórun à nínúdídùn pèlú ìṣèdá Rè gégé bí Òun tikalara Rè. Omọdé kan gbádùn ohun ti Olórun sèdá, ohun gbogbo jé agbayanu sí i.

Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Kí ni mo le ro pé mo ní-lò láti jèrè ìdùnnú? Kílo túmọ̀ sí láti nínúdídùn si ìṣèdá Olórun? Kí nìdí tí mo kà èrùpe sí èpè dípò
Ìbùkún?

À mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Si gá síbẹ̀ fún Ènì tó ga jùlọ àti Òṣìṣẹ́ Olórun © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 12Ọjọ́ 14

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.

More

We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org