Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ
Ìdùnnú tí onígbàgbọ́ le fún Olórun jé ògidì adùn tí Olórun fàyè gbà ẹni mímọ́, àtipe ó jé ohun ìtẹ́lógo gan láti rí i bí ìdùnnú kékeré tí à fi Fu ún. À fi ìgbẹ́kẹ̀lẹ́ wá nínú Olórun títí de aaye kan, nígbà náà àwa sowipé, “nìsinsìnyí mo gbọ́dọ̀ sa gbogbo agbára mi.” àwon ígbà wá nígbà tí kò si agbára ènìyàn láti se, nígbà tí gbogbo agbára àtọ̀runwá gbọ́dọ̀ wá ni fifi sílè láti sise, àtipe Olórun retí pé lara àwa to mò Ó láti ní ìdánilójú nínú ijáfáfá àti agbára Rè. À ní láti kó ohun tí àwon Apẹja náà kó, pé Gbẹ́nàgbẹ́nà náà tí Násárétì túbọ̀ mò dáadáa jú wón lo bí wón se ṣàkóso o̩kò̩. Se Jésù Kristi jé Gbẹ́nàgbẹ́nà, tàbí se Ó jé Olórun simi? Tí Ó ba jé ènìyàn sáà, èéṣe tí o jè kí Ó gba olutọju o̩kò̩ ojú omi náà? Èéṣe tí ó gbàdúrà sí Í? Súgbòn tí Ó ba jé Olórun, lẹ́yìn náà akikanju tí ó pọ̀ tó láti lo sí òpin-ojú àti láì tú ìdánilójú rè nínú Rè ká.
Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Ǹjẹ́ mo ti jíròrò rí èrò pé mo le tàbí ó yẹ kí fi ìdùnnú fún Olórun? Se mo mó ohun tón mú ìdùnnú fún Olórun? Ní àwon ònà wo ní mo le fi ìdùnnú fún Olórun?
A mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Ibi Ìrànlọ́wọ́ © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí
Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Ǹjẹ́ mo ti jíròrò rí èrò pé mo le tàbí ó yẹ kí fi ìdùnnú fún Olórun? Se mo mó ohun tón mú ìdùnnú fún Olórun? Ní àwon ònà wo ní mo le fi ìdùnnú fún Olórun?
A mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Ibi Ìrànlọ́wọ́ © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí
Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.
More
We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org