Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ
Olúwa wà sọ̀rọ̀ nípa ìdùnnú tí siṣàwárí ohun to sọnù. Sí mi èyí dùn mọ́ mi jù nígbàgbogbo: Olúwa fé wòrán nípasẹ̀ àwon ojú mi. Olúwa fé ronú nípasẹ̀ opọlọ mi. Olúwa fé ṣiṣẹ́ nípasẹ̀ àwon owó mi. Olúwa fé láti gbé àti rìn ní ara mi fún ète kan—láti sá tẹ̀ lé àwon tótí sonù láti ojú ìwòye Rè. Ṣé mo n jé kí Ó rìn àti gbé nínú mi?
À lè so àwon ìṣẹ̀lẹ̀ tí èmí lè jé ayédèrú. " Simi nínú Olúwa” lè yí pa dà sí onítara ìsìn “dípẹtà” nínú ọ̀rọ̀. kí ni gbogbo ọ̀rọ̀ wa nípa ìsodimímó máa yorí sí? Ó yé ko yorí sí pé ìsimi nínú Olórun tó túmọ̀ sí wíwà ní ọ̀ọ̀kan pèlú Rè gégé bí Jésù se—kì í se aláìlẹ́bi nìkan ní níwájú Olórun, sùgbón ní ìdùnnú jinlè sí Í.
Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Se mo ń gbádùn sisàwárí ohun tó sonù? Se mo jé onikópa tonítara nínú ètò Olórun láti wà àti láti gbá àwon tó sonù là? Báwo ní mo se lè jèbi fún sisèdá ayédèrú ní tèmí? Se mo n se igbélárugẹ eyikeyii irú ìsimi yàtọ̀ sí wíwà ní ọ̀ọ̀kan pèlú Jésù àti aláìlẹ́bi sí Olórun?
A mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Àwon Òsìsé Olórun àti Ibi Ìrànlọ́wọ́ © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.
More
We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org