Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Ọjọ́ 30 nínú 30

Ìfọpẹ́hàn fún Ọlọ́run, ìdùnnú Olúwa jé ìrírí ìsinsìnyí gan-an, àtipe o kọjá ìrírí ti a mọ̀, nítorí ìdùnnú ti Olúwa mú wa wọnú ìnímọ̀lára Olórun, àti ọlá to ṣe pàtàkì ni ara wa ni olá ti Olórun. Ǹjẹ́ a ti mọ̀ dájú pé a ti ṣẹ̀dá Omo Olórun nípasè ìràpadà àgbàyanu Rè? Èyí ni ògo tí àwon eni mímó níhìn-ín àti nìsinsìnyí—ògo gan-an fara hàn kedere ni ayé gan-an.

Olórun alágbára gíga tí di ohun alàìlera ju lo sí ìṣèdá Rè, ọmọ ìkókó. Eni mímó tó ti dàgbàdénú da bíi omo kékeré, irorùn pátápátá mbe àti ìdùnnú. Máa gbé ìgbésí ayé ti Olórun yóò jé ki o gbé àtipe ìwọ yóò dàgbà kéré lọ́jọ́ orí dípò kí dàgbàlagbà. Isọdi ọ̀tun àgbàyanu wà fún o kete nígbà ti o ba je ki Olórun ni ònà ti Rè. Ti òtútù n ba mú o gan, nígbà náà di àtúnbí àti túbọ̀ se sí.

Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Ǹjẹ́ mó n gbé àwon àṣà wò tí wón wa ni ìbámu pèlú ìjẹ́mímọ́ ti Kristi? Ní àwon ònà wo ni a n gba ṣèdá Olórun nínú mi? Ǹjẹ́ mó tí múra tán láti tún jèrè ìdùnnú bíi tàwon omodé?

A mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Oroinuokan tí Ìgbàlà, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 29

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.

More

We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org