Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Ọjọ́ 24 nínú 30

Kòsóhun tó ń múnú bíni jù ìmọ̀ràn lo, “túbò ma rẹ́rìn-ín”; èyí jé ayédèrú, titànyinrin tó máa fizzle out láìpẹ́. Ohun kan tí Jésù Kristi se fún ènìyàn ni láti se e ni titànyinrin, kì í se titànyinrin àtọwọ́dá. Ìdùnnú ti Jésù fún ènì jé àbájáde ìtẹ̀sí-ọkàn wa ni wíwà lọ̀ọ̀kan pèlú ìtẹ̀sí-ọkàn Tirè. Èmí Olórun yóò kún wa láti kún àkúnya tí à bá ń ṣọ́ra láti wà nínú ìmólè. A kò ni isé láti wa ni áìlera ní okun Olórun.

A kò ní isé láti sò fún Olórun pe a kò lè dúró mo; ó yẹ kí Olórun wa ní òmìnira láti se pèlú wa bí Ó se yàn, gégé bí O ti se pèlú Omo Rè. Nígbà náà ohunkóhun tó bá ṣẹlẹ̀ ní ayé wa yóò kún fún ìdùnnú.

Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Se ẹ́rìn-ín mi jé ti ipá tàbí àbínibí? Se ìdùnnú mi kún fún ìrètí ìdíbọ́n tàbí tìtànyinrin ní inú? Se mo gbẹ́kẹ̀lẹ́ pe Olórun lè fún mi ni ìdùnnú nípase àwon ìsòro tí mi kò yàn?

À mú àwon àyọlò òrọ̀ láti Ibi Ìrànlọ́wọ́, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 23Ọjọ́ 25

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.

More

We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org