Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Ọjọ́ 23 nínú 30

Ní àwon ìpele kan ni ìgbé ayé tèmí à ní èròǹgbà oníjìnnìjìnnì pé gbogbo ohun tí à ní, à gbódò juwọ́ won sílẹ̀. Nínú Bíbélì ìtumọ̀ ebọ ní mòómò fifún Olórun ní ohùn tó dáa jù lo pé kí Ó lè se ni Tirè àti témi títí láé: bí mo bá rọ̀ mọ́ o máá pàdánù rè, àti Olórun náà. Olórun so fún Ábúráhámù láti fi Isaaki rúbọ fún ebo sísun, àtipe Ábúráhámù se ògbufọ̀ è láti tumọ̀ si pé ó ní láti pa omo rè. Àmó lórí Òkè Moriah Ábúráhámù pàdánù àṣà òdì nípa Olórun àtipe gbà ìjìnlẹ̀ òye òtún níti ohun tí ebo sísun tumò si: ebo tó wà láàyè (Róòmù 12:1-2). ńṣe ló dà bí ẹni pé a ní láti juwọ́ ohun gbogbo sílẹ̀, pàdánù gbogbo ohun tí à ni, àtipe dípò kí Ẹ̀sìn Kristi mú ìdùnnú àti ìrọrùn wá, ó so wa di akúùṣẹ́; títí di ìgbà lójijì à rí i pé ète Olórun nipé à ní láti kópa nínú ìdàgbàsókè ìwà rere tí àrawa, àtipe à n se èyí nípasè ebo àdánidá sí èmí nípa ìgboràn, kì í se ìjiyàn àdánidá, àmó síse ìrúbọ è.

Àwọn ìbéèrè Ijiroro:Kí ní àwon èròǹgbà òdì nípa Olórun ti mo mmú gírígírí tó fà mi sẹ́yìn kúrò nínú ìrírí ìdúnnú?

À mú àwon àyọlò òrọ̀ láti Òun Yóò Se Mi Lógo, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 22Ọjọ́ 24

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.

More

We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org