Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Ọjọ́ 26 nínú 30

Èsè, ìjìyà, àti ìsọdimímọ́ wón kì í se àwon ìsòro tí okàn, súgbòn ohun ìdájú gan-an tí ayé—àwon ohun àdììtú tó jí gbogbo àwon ohun àdììtú mìíràn dìde títí okàn yóò fi simi nínú Olórun. Oh, ìdùnnú aláìṣeéfẹnusọ tí mímò pé Olórun jọba, pé Òun ni Bàbá wá, àtipe àwon òfuurufú jé àmó “eruku esè Rè”! A gbé ẹ̀sìn ìgbé-ayé karí àti gbé ró àti dàgbá lórí ìgbẹ́kẹ̀lẹ́ àtayébáyé gbogbo ọkàn, ìyípadà ológo nípa ifé; ọ̀rọ̀ rírùn pé ayé lè wa ní sise nìkan nípa àwon òǹwòran, láé nípa ènì mímó.

Olúwa, òunjẹ díẹ̀ tí mó ń fún Kristi ti ó ń gbé nínú mi; O Olúwa, E dáríjì mi. E kún mi pèlú òpò làákàyè ti ìdáríjì Yin fi jẹ́ pé mi kò ní ìdùnnú nínú ìgbàlà Yin nìkan, àmó kún mi pèlú Èmí Yin fún isé nibi.

Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Se àwon ìṣòro, àwon àìṣedéédé, àti àwon ohun àdììtú tí ayé mú mi láti juwọ́ sílẹ̀ ni àìnírètí tàbí fún mi nidánilójú láti gbẹ́kẹ̀lẹ́ Enì tó ràn mi jáde láti kéde ìhìn iṣẹ́ pè Ifé yóò ṣẹ́gun èsè àti ìjìyà?

A mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Èkọ́ Kristẹni àti Kíkànlẹ̀kùn Olórun, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 25Ọjọ́ 27

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.

More

We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org