Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Ọjọ́ 29 nínú 30

Èyíkéyìí okàn tí kó ni ibi yàrá àdáwà pèlú Olórun wà ni ewu nípa tẹ̀mí. Se à tí fàyè gbà kí ibi yàrá àdáwà làti wó lulè tàbí kó sórí pèlú pẹpẹ tó rewà, àti àwon ènìyàn tón ńkọjá lọ sò pe, “ onísìn ni ènì yìí gbódò jè.” Irú pẹpẹ yìí jè àbùkù sí isé Olórun tó jinlè ni àwon okàn wa. Olórun fún wa láǹfààní kí a lè kó púpò àti púpò ìdùnnú tó jinlè gan-an ti àdáwà pèlú Olórun nínú òkùnkùn tí álé àti síhà kùtùkùtù òwúrọ̀ àfẹ̀mọ́jú.

Nínú ìwé Ìfihàn, Jésù Kristi tóka sí ara Rè gégé bí “àkókó áti ìkẹyìn.” inú ààrín èyí ni ènìyàn se yìyàn wón; ìbèrè áti òpin kò yí padà pèlú Olórun. Àwon àṣẹ ti Olórun ni àwon ààlà náà ni ènìyàn se tí ìsoríkọ́ ti rè tàbí ìdùnnú.

Àwon ìbéèrè Ijiroro: Ibo ni ibi yàrá àdáwà mi pèlú Olórun? Se mo gbádùn dí dáwà pèlú Olórun tàbí mo ni ìháragàgà láti sisé? Se mo béré óojojúmó nípa bibéèrè lódó Olórun ohun ti o yé kí n se áti parí e nípa bibéèrè báwo ni ma se e?

À mú àwon àyọlò òrọ̀ láti Òun Yóò Se Mi Lógo áti Si gá síbẹ̀ fún Ènì tó ga jùlọ © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 28Ọjọ́ 30

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.

More

We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org