Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ
Nìgbàkígbà tí àwọn ángèlì ba wá sí ilẹ̀-ayé yìí wón wá ni ìbújáde pèlú ìdùnnú èyí tó ní láti dúró lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ (cf. Lúùkù 2:13). Ilẹ̀-ayé yìí dá bí yàrá àìsàn, àtipe nígbà tí Olórun rán àwon ángèlì Rè sibí Ó ni láti sọ pé—“è dáké jẹ́ẹ́ báyìí; won n sàìsàn pèlú èsè tó jé pé wọ́n kò lè lóye ẹ̀rín aláriwo yín.” Nìgbàkígbà ti ìbòjú náà máa ṣí kúrò ẹ̀rín àti ìdùnnú ń bẹ. Àwon èyí ní àwon àmì-ìdámọ̀ tó jé tí Olórun àti ètò àwon ohun Olórun; ìrẹ̀ sílẹ̀ àti ìdálóró àti ìsoríkọ́ jé àwon àmì-ìdámọ̀ tí gbogbo tí kò jé tí Olórun.
Ní gbogbo ìgbà tí a bá ní òwò ìdúnàádúrà pèlú Olórun lórí májẹ̀mú Rè àtipe ní láti jáwọ́ pátápátá lórí Olórun, kò sí làákàyè ìtẹ́wọ́gbà nínú rè, kò sí èròjà ènìyàn rárá, àmó irú gbogbo làákàyè béè wá pọ̀ lápọ̀jù pátápátá ti wíwà ní inú ìṣèdá Olórun pe ìyípadà ológo nípa àlàáfíà àti ìdùnnú ni.
Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Ìbòjú èkó èké wo ni o n fà mi sẹ́yìn kúrò nínú níní ìrírí ìdùnnú Olúwa? Ìgbà wo ni mo bújáde pèlú ìdùnnú kẹ́yìn? Báwo ni agbára láti ṣẹ̀dá àti ìdùnnú tan mọ́?
A mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Aímọ̀ Ibi, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.
More
We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org