Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ
Jésù Kristi kì í se Olùgbàlà nìkan, Òun ni Oba, àtipe Ó ní agbára láti mu ohunkohun àti ohun gbogbo ṣẹ láti ọ̀dọ̀ wa ni ọgbọ́n inú Tirè. A sòrò nípa àwon ìdùnnú àti àwon ìtùnú ti ìgbàlà; Jésù Kristi sòrò nípa gbigbé alágbèélébùú àti títẹ̀ lé È. Díè láàárín wa lo mò ohunkohun nípa ìdúróṣinṣin si Jésù Kristi. A ṣíjú wo Jésù Kristi gégé bí àpeere tó dára jù lo tí ìgbé ayé Kristeni; a kò ronú È gégé bí Olórun alágbára gíga jù lọ tó gbé àwọ̀ èèyàn wọ̀, pèlú gbogbo agbára ní òrun àti ayé. A se E ni elegbé, Ènì kan tó n mbe lójú ogun ayé ní èémí jù ìyókù lo àtipe O yí ká láti yá ọwọ́. A ni ìbálò pèlú È bí ẹni pé Ó jé ọ̀ọ̀kan lara wa; a kò bó bàtà kúrò lẹsẹ̀ wa nígbà tí Ó bà n sòrò. Jésù Kristi ni Olùgbàlà, àtipe Ó gbà wa là sínú pọ́ńbélé àti ipò olúwa mímó Tírè.
Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Ìdúnnú wo ní mo ti rí nínú ẹbọ? Se mo gbà ìdúnnú tó túbọ̀ pọ̀ sí i láti níní Jésù gégé bí a ẹlẹgbẹ́ jù gégé bí Oba? Se mo túbọ̀ kún fún ìdùnnú láti ronú níní àkóso nínú ìjoba Olórun tàbí ti ìjìyà tó te e síwájú sí i l?
À mú àwon àyọlò òrọ̀ láti Òun Yóò Se Mi Lógo, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.
More
We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org