Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ
Ti àwon ipò rè bá jé ìdánwò nísinsìnyí gan-an, rántí ìgbà tí wón kò jé ìdánwò, àtipe o máa yà ó lẹ́nu sí agbára-ọ̀tún tìkara ènì nínú ọkàn-àyà ènìyàn láti yípadà láti ohun kan sì òmíràn. Báwo ni irora ọkàn ńláǹlà okàn ènìyàn lè fàyè gbà, àtipe báwo ni ìdúnnú se pò tó! Tí à bá pàdánù agbára ti síse àyípadà láti oókan sí òmíràn, à múnú bí ìwàdéédéé. Èmí Olórun dapadà sípò àti mú ìwàdéédéé si ọ̀tún.
Síṣe ìwàásù Ìhìnrere ti “ọ́yàyà,” nígbà tí ènìkan kò lè lọ́yàyà. Sọ fún un láti wo ègbé tó tàn yòò ti àwon ohun nígbà tí kò si ègbé tó tàn yòò jé ohun yẹ̀yẹ́ láti so fún a eja láti tẹ́tísílẹ̀ sí oókan lara àwon sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ Handel. Ó jé gégé bi òtúbáńtẹ́ láti so fún ènì tí da lẹbi-ẹ̀ṣẹ láti lọ́yàyà. Ohun tó nílo ni oore-ọ̀fẹ́ Olórun láti yí I padà àti láti mú u sínú ìrúwé-rere ti ìdúnnú.
Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Se mo tẹ̀dó sí ọ́yàyà dípò ìdúnnú? Se ìgbọ́kànlé mi nínú Olórun tó kí mò lè ni ìrírí ìdúnnú kódà lásìkò àwon ìgbà ìbànújẹ́? Se ìrírí mi ti oore-ọ̀fẹ́ tóbi ju èse mi lo?
À mú àwon àyọlò òrọ̀ láti Ìrònú òun ìhùwà Ti Bíbélì, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.
More
We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org