Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ
Kí ni ìdùnnú tí Olúwa Jésù Kristi? Ìdùnnú Rè wa nínú pé Ó parí pátápátá isé tí Bàbá Rè gbé fún U láti se; àti irú ìdùnnú kaánnà ni à yóò jíǹkí fún gbogbo o̩kùnrin àti obìnrin tí à bá bí nípa tí Olórun àti tí à sọ di mímọ́, nígbà tí wón bá se ìmúṣẹ isé ti Olórun ti gbé fún wón láti se. Kí ni isé náà?
Láti jé ènì Mímó, a n rìn, n sòrò, n gbé, ìwé ohun ti Olórun Olódùmarè lè se nípasè Ètùtù tí Olúwa Jésù Kristi—oókan nínú ìdánimọ̀ pèlú ìgbàgbọ́ Jésù, oókan nínú ìdánimọ̀ pèlú ifé Jésù, oókan nínú ìdánimọ̀ pèlú Èmí Jésù títí di ìgbà ti à so wa di oókan nínú Rè pé àdúrà-àlùfáà gíga kò nìkan bèrè láti máa fidáhùn sí, sùgbón ó farahàn kedere à ti dáhùn è—“pé kí wón lè jé oókan, síbẹ̀ gégé bí à tí jé.”
Jóòbù fún ni ní ìfi hàn si èròǹgbà tuntun tí Olórun; ìrètí rè ni pé olùdarí yóò dìde tí kò ni dá Olórun láre nìkan, àmó dá òun náà láre. Ìbànújẹ́ lo mú Jóòbù wá sibi yìí, àtipe ìbànújẹ́ ni ohun kan tó máa se; ìdùnnú kì í se, ásìkí kò n se náà, sùgbón ìbànújẹ́ n se.
Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Ní ònà wo ni mo n gbìyànjú láti wá ìdùnnú nígbà tí emi kò rìn àti n sọ̀rọ̀ bí Jésù? Kí ló mú mi ró pé èyí ṣeé ṣe?
À mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Ìtẹ́wọ́ gbà Sí Olórun àti Láyà láti túbọ̀ ṣe dáadáa sí © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.
More
We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org