Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ
Rìnnàkore tí ìkùnà ni! Pé òun ni ònà tí Póòlú n gbá wò óko ẹrú rè. Kò fé kí wón soríkọ́ lórí àkọọ́lẹ̀ rè, tàbí láti gbèrò pé ìdènà tí bá ète Olórun; o so pé kòsi ìdènà fún u, àmó ó tesíwájú sí i. Àwon ohùn gan-an da bí àjálù tí yipada yorí sí èyí tó láǹfààní jù lo,torí pé lórí àkọọ́lẹ̀ yìí okàn rè kún pèlú ìdúnnú, àti àkíyèsí yíyò yóò jáde wá.
Èmí ìgbọràn fún mi ní ìdùnnú lòpò sí Olórun jù ohunkóhun mìíràn lórí ilè ayé. Nígbà tí ifé Olórun báa ti ta sílè káàkiri nínú òkàn mi (Romans 5:5), Mo lẹ́mìí èdá Olórun, àtipe mo mò pé nípa ìgbọràn mi pé mo nifé Rè.Sisè wíwọ̀n tó dáa jù tí ìgbé ayé tèmí kì í se yíyò ayọ̀ púpọ̀ jọjọ, sùgbón òun ni ṣisègbọràn.
Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Àjálù wo lo ti yipadi àǹfààní? Ìdùnnú wo ni mo bá ti pàdánù tí mi ko báa ti rìn pèlú Olórun nípasè ìpónjú?
À mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Ìtẹ́wọ́ gbà Sí Olórun àti Láyà láti túbọ̀ ṣe dáadáa sí © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.
More
We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org