Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ
Ká sọ pé Olúwa wa ti se wíwòn ayé Rè nípa bóyá tàbí Kò jé ìbùkún sí àwon ẹlòmíràn. Kí nìdí, Ó jé “òkúta ikọsẹ̀” sí egbèrún, sí àwon aládùúgbò Rè gangan, sí orílè èdè Rè, nítorí nípase Rè wón sọ̀rọ̀ òdì sí Èmí Mímó, àti nínú orílẹ̀-èdè Rè “Kò [se] òpò isé alágbára ńlá nibe nítorí tí àìgbàgbọ́ wón” (Matthew 13:58).
Tí Olúwa wa ba ti se ìwọ̀n ayé Rè nípa abajade rè gangan, Ó máa tí kún fún irora ọkàn ńláǹlà. À kò si nibí láti jèrè àwon okàn, láti se dára dára sí àwon ẹlòmíràn; iyen ni abajade lasan, àmó kì í se ète wa, àti èyí ni níbi tí òpò lara wá dáwọ́ dúró láti jé ọmọlẹ́yìn. À máa tẹ̀ lé Olórun níwọ̀n ìgbà tí Ó bá mú wá jé ìbùkún sí àwon ẹlòmíràn, súgbòn nígbà tí Kò ba jé à kò ní tẹ̀ Lé. ìdùnnú ohunkóhun, láti a abẹfẹ́lẹ́ tí koríko sókè, ní láti se ìmúse ìdí ti à sẹ̀dá fún—pé o yé ka jé fún ìyìn ògo Rè.
Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Báwo ni mo se ìwòn ayé mi? Se mo lo ìwọ̀n Olórun tí ìgbàgbọ́ àti ìwà-bí-Ọlọ́run tàbí ìlànà ayé tí gbígbajúmọ̀, àmújáde, àti ṣiṣẹ́ lọ́nà tó já fáfá?
À mú àwon àyọlò òrọ̀ láti Ifé tí Olórun, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.
More
We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org