Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ
O jé ohun tó rọrùn nígbàgbogbo láti se àìbìkítà sí Ọkùnrin tàbí Obìnrin tó mọ̀ọ́mọ̀ tẹ́wọ́ gbà ète ayé rè láti ọ̀dọ̀ Jésù Olúwa. ọ̀pọ̀ lara wá jé alafarawé tí àwon elòmíràn; a se isé Kristẹni nítorí enìkan sọ fún wá láti se. À gbọ́dọ̀ téwó gbà iṣẹ́ òjíṣẹ́ wá, èyí to jé láti jẹ́rìí sí i Ìhìnrere tí oore ọ̀fẹ́ tí Olórun, láti ọ̀dọ̀ Jésù Kristi fúnra Rẹ̀, kì í se láti ọ̀dọ̀ àwon Kristẹni míràn. ídùnnú ní èsì ìmúṣẹ pipé tí ohun tí À ṣẹ̀dá ènìyàn fún. Ó pondandan láti máa bá a nìṣó láti padà sí ohun tí Májẹ̀mú Tuntun béèrè lówó wá ni láti téwó gbà nípa àrawa. Isé àkókó wá tí à yàn láàyò jùlọ tí à téwó gbà kì í se láti ràn ènìyàn lówó, súgbòn láti ṣègbọràn sí Olórun, àti nígbà tí à bá téwó gbà iṣẹ́ tí à yàn láàyò náà à wolé sínú ibatan pèlú àwon táa tẹ́ńbẹ́lú àti àwon tí wón pa tì.
Olórun sú mo ìtòsí lẹsẹ̀kẹsẹ̀ àti ni ágbára tó pọ̀ jọjọ o jé pé mo gbà ọ̀pọ̀ àti ọ̀pọ̀ ídùnnú nínú ìdánílójú mi nínú Rè pèlú dínkù àti dínkù ní iṣọ́ra bí mo se nímọ̀lára.
Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Se mo fara wé àwon ẹlòmíràn láti yera fún wiwá iṣẹ́ òjíṣẹ́ témi? Ìjẹ́rìí wo ni Olórun tí fifún mi àtipe láì fifún elòmíràn? Ìhìn iṣẹ́ ídùnnú wo ní Olórun tí fifún mi láti polongo?
À mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Ìrònú òun Ìhùwà tí Ìràpadà àti Sá eré ìje Tòní, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.
More
We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org