Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Ọjọ́ 18 nínú 30

Mimọ lẹkun-un-rẹrẹ pé agbára mi máa ṣèdíwọ́ fún ìpèsè ayé ti Olórun jé àpilẹ̀kọ tí ń lani lóye. Ènìyàn kan to ní òye àrà ọ̀tọ̀ bá a mu rẹ́gí láti gbára lé òye rè dípò lé Olórun. Ènìyàn to ni owó bá a mu rẹ́gí láti gbára lé dípò Olórun. Nítorí náà òpò lára wa ti fọkàn tán ohun a ti ni ònà ohun ìní dípò lé Olórun pátápátá.

Gbogbo àwon orísun agbára wònyí jé orísun
àìlera ni ìlópo méjì. Súgbòn nígbà ti a mo lẹkun-un-rẹrẹ pé igbé ayé we ni tòótọ́ wani “ipamó pèlú Kristi nínú Olórun,” pé a jé “pípé nínú Rè,” ẹni tí “gbogbo ekún rẹ́rẹ́ Ọlọ́run Mẹ́talọ́kan ti ara gbé inú Rè,”nígbà náà agbára Rè máa tàn yòò àti ifihàn kedere ni ẹni kíkú ẹran-ara wa. Olórun fún wa pé Èmí Rè lè mú olúkúlùkù wa síbì tí a tin kẹ́kọ̀ọ́ àsísrí àti gbádùn wipé agbára Rè jẹ́pípé nínú àwon àìlera wa.

Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Báwo ni agbára mi se máa ń ṣèdíwọ́ fún Olórun? Báwo ni àwon ohun àmúṣọrọ̀ mi se máa ṣèdíwọ́ fún Olórun? Kí ni àsísrí naa ti o wani ipamó si mi nítorí mò kò láti gbára lé Olórun?

A mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Oṣiṣẹ Ọlórun © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 17Ọjọ́ 19

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.

More

We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org