Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Ọjọ́ 12 nínú 30

Gbogbo ohun tí o sòkùnkùn àti rúnilójú báyìí gan ní ojó kan ló máa mọ́lẹ̀ kedere, gégé bí o tàn yòò àtipe ìdùnnú bíìtì, bí à tí rí. Abájọ ti Olórun fún wa nìmọ̀ràn láti ní sùúrù. Díẹ̀ díẹ̀ à máa mú ohun gbogbo wá sínú ìmólé títí à o fi lóye gégé bí Jésù Kristi tí lóye. Ódindi gbogbo ayérayé la máa gbé pèlú óye àti mímo Olórun, àti dúpẹ́ lọ́wọ́ Olórun, a le bẹ̀rẹ̀ láti mo O nilè nibí. Ayé ìsodimímó tumọ̀ sí pé à bẹ̀rẹ̀ si ni óye Olórun àti láti fi hàn ayé ti Omo Olórun eran ara kíkú wa.

Gbogbo ìmọ̀ bíìtì tí Olórun tí à ní kún wa pèlú ìdùnnú atóbimáṣeéfẹnusọ. Bí à ba lóye Olórun lori èyíkéyìí kókó kan à má mó ohun kan tí ìdùnnú tí Jésù ní. Ó jé ohun ìní agbayanu, o jé Irú ìwà tí Jésù gan-an.

Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Se mo gbádùn ìṣípayá ìyára - ilọ́ra tí Olórun tàbí se mo di aláìnísùúrù pèlú àìní kánjúkánjú Rè? Bí Olórun kò ba sáré, Kí ni ìdí mi? Báwo ní mo se le gbádùn ìmọ̀ tí mo kò ba gbádùn àwárí?

À mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Ogún ìní wa Títànyòò © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 11Ọjọ́ 13

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.

More

We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org