Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ
Ó jé ohun agbayanu láti rí ọkùnrin tàbí obìnrin gbé nínú ìmólé tí ó kò lè rí. Ó lè só nígbàgbogbo nígbà tí ènìkan ní ìdíwọ̀n tí a kò lè fojú rí; ohun kan mbe tón mú wón dùn nígbà tí láti onírúurú ironú lórí mìíràn o yé kí wón kan. Iyen jé àmì Kristeni. Kó yà kúró lásìkò ígbà ewu. Ó ní ìdákọ̀ró tó mú láàárín ìbòjú. Nígbà tí à mo pé ígbà kan bo nígbà tí a yóò gbogbo ohun ṣàlàyé lẹ́kùn-ún-rẹ́rẹ́, ó mú èmí wa má kún fún ìdùnnú tí à kò lè fó.
O Olúwa Olórun, ohun ti Ẹ jé si mi ni mo bẹ̀rẹ̀ si ni lòye—jù ú ìmọ́lẹ̀ owuro lo, jù ú ìdùnnú àti ìlera, jù ú gbogbo àwon ìbùkún Yín lo. Òye mi là lákọ̀tun ni owuro yìí àtipe E se mi ni ìmólé jákèjádò pèlú ìdùnnú Yín.
Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Báwo ní mímọ ènì tón di ọ́jọ́ iwájú mú ṣinṣin múmi kì n má bàa yẹra sínú àìnírètí? Ìmọ́lẹ̀ wo ni mo ní-lò láti kó àfiyèsí lori didúró lori irin àjò tí ìdùnnú? Nibo ní mo ní-lò láti gbé ìdákọ̀ró mi ró si láti mú mi yera fún yiyà kúró nínú ipa-ọ̀nà?
À mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Ibi ìrànlọ́wọ́ àti kíkàn ilèkùn Olórun © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.
More
We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org