Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ
Ní gbogbo ìwọ̀n ìdúnnú n gbé nínú okàn. Báwo ni Kristeni lè kún fún ayò (tí ayò ba gbára lé àwon ohun tón selè) nígbà tí Ó wa mínú ayé nibi tí ésù tín se gbìyànjú láti fa àyídáyidà si àwon okàn kúrò lòdò Olórun, nibi tí à tín dá àwon ènìyàn lóró tín nípa ti ara, nibi ti àwon mìíran ti sorí kọ́ àtipe wón kò láyè? Ó máa jé òpin òpò akúùṣẹ́ ìmọtara-ẹni-nìkan láti láyọ̀ lábẹ́ irú àwon ipò yi. Sùgbón okàn tó ní ìdùnnú kì í se àbùkù láé, àtipe ìdùnnú kò ní ìfówo kàn nípasè àwon ipò òde ara láé.
Bíbélì so àsọyé wọ̀ǹtìwọnti nípa ìdúnnú, àmó kò sọ̀rọ̀ nibikibi nípa Kristeni “ tó láyọ̀”. Ayò gbára lé ohun tó n ṣẹlẹ̀; ìdùnnú kì í se. Rántí pé, Jésù Kristi ní ìdùnnú, àtipe Ó gbàdúrà “pé wón lè ní ìmúṣẹ ìdùnnú Mi nínú ara wón.”
Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Kí ni ìsirò ìfiwéra ti ìdúnnú si ayò ní ayé mi? Ìgbà melo ní mo fún àwon ipò láàyè láti se ìpinnu ìmọ̀lára mi? Ìgbà melo ni mo máa n ní ìdúnnú?
À mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Ìrònú òun ìhùwà Bíbélì © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.
More
We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org