Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ
Ìdùnnú ti Jésù sùn nínú mimò pé gbogbo agbára tí é̩dá Rè wa ní irú ìbámu pèlú Bàbá Rè pé Ó se ifé Bàbá Rè pèlú ìnúdídùn. Lára wá n lọ́ra láti se ifé Olórun; à se ifé Rè bí ẹni pé bàtà wa jé irin àti òjé; à se ifé Rè pèlú ìmí kanlè ńlá àti pèlú ẹ́gbẹ̀ẹ́ enú wa silè, bí ẹni pé ifé Rè ni ohun tí ó ṣàyàgbàǹgbà jù lo lori ilè-ayé. Sùgbón nígbà tí à bá sàtùnse àwon ifé wa àti mú wá sinú ìbámu pèlú Olórun, ìnúdídùn ní i, ìdùnnú opọ̀ jaburata- tó ga jù, láti se ifé Olórun.
Bá àwon eni Mímó sọ̀rọ̀ nípa ìjìyà àtipe wón ń wò è pèlú kàyéfì ńlá. “Ìjìyà? Ìjìyà wo?” Ìjìyà jé òrò ìtumọ̀. Fún àwon eni mímó ó jé ìnúdídùn pupọ̀ jù nínú Olórun; kì í se ìnúdídùn nínú ìyà, àmó ti ifé Olórun bá má jálẹ̀ sí ìjìyà, ìnúdídùn wá nínú ifé Rè.
Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Kí nìdí tí mo fi n lọ́ra láti se ifé Olórun? Kí nìdí tí èsìn èké jẹ́ kí mi ronú pé, Olórun kó fé jé kin láyọ̀? Nígbà wo ní mo ní ìrírí ìnúdídùn si sisé ifé Olórun?
À mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Àwon ìwà rere ìpìlẹ̀ ti ayé © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.
More
We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org