Oswald Chambers: Ìdùnnú - Agbára Nínú OlúwaÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Ọjọ́ 3 nínú 30

Nígbà tí ènìyàn bá kúrò ni ódò Bíbélì, Olórun ní orúko lásán tí à fún ìtẹ̀sí gbogbogbòò èyí ti o sùn ifé ènìyàn síwájú sí i—pé Olórun àti Jésù Kristi àti Èmí Mímó wón wà lásán fún ìbùkún wà, láti sùn ifé wà síwájú sí. Nígbà tí à wá sinú Májèmú Tuntun á rí ìdàkejì èrò gan- an, pé nípasè sọ wá dọ̀tun à ti mú wá wonú irú ìbámu àti ìṣọ̀kan pèlú Olórun pé à rí pé pèlú ìdùnnú nla pé ó yé kí a sìn ifé Tirè.

Tá a bá máa bá a lọ nínú ìmọ́lẹ̀ pèlú Olórun, ayé wa dà bí ti ọmọdé kan, rorun àti kún fún ìdùnnú jákèjádò. Ó tó fún ọmọdé kan láti mò pé bàbá rè fé kí ó se àwon ohun kan àtipe ó kó láti fa lóríokun tó jù tirè lo.

Àwọn ìbéèrè Ijiroro: Se mo n lo Olórun láti jé kí àwon ifé okàn mi síwájú tàbí se mo n sìn Olórun láti jé kí ti Rè síwájú? Se mo n lo Bíbélì láti fi hàn dájú pé mo tọ̀nà tàbí láti rídìí níbi tí mo tí ṣàṣìṣe? Se mo ni ìdùnnú láti rídìí níbi tí mo tí ṣàṣìṣe kí à lè mú mi tọ̀nà?

À mu àwon àyọlò ọ̀rọ̀ láti Ìmọ̀ ọgbọ́n orí èsè© Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 2Ọjọ́ 4

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Joy - Strength In The Lord

Sàwárí òye ti Oswald Chambers, olùkọ̀wé Sísa gbogbo ipá fún Gíga jùlọ, nínú ìṣúra èyí òye inú nípa ìdùnnú. Àwon àyọlò ọ̀rọ̀ tún tayọ nínú èkó kíkà kọ̀ọ̀kan láti Chambers nírẹ̀ẹ́pọ̀ pèlú àwon ìbéèrè fún Ijiroro tiré gan. Bí ó se mísí o àti pè o níjà pèlú òyé rè tó rorùn àti òye Bíbèlí, wa a rí ara re n fé láti lo àkókò sí i ni bibá Olórun sòrò.

More

We would like to thank Discovery House Publishers for providing this plan. For more information, please visit: www.utmost.org