Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Orísun àlàáfíà ni Olórun, ko kin se emi fun arami; kò figba je àlàáfíà mi ṣugbọn nígbàgbogbo ti Tire, atipe ni kete ti O ba fà sẹ́yìn, ko si nibe. Timo ba gba ohunkóhun laye lati di ojú, ìrísí ojú, ìrántí, ijíròrò ti Jésù Olúwa wa láti ọ̀dọ̀ mi, nígbà náà yálà ma wa ninu ìdààmú tabi kin ni ní ayédèrú ààbò.
Olúwa, nínú ìmọ̀lára mi ni owurọ yi, ogunlọ́gọ̀ àwọn ohun kekere n fa idààmú atipe mo mu wọn wa tààrà síwájú E. Nínú òye Yin, E wí, “Àlàáfíà, parôrô” ati aye mi to wa ni ètò ma jẹ́wọ́ si ewà àlàáfíà Yin.
Ìbéèrè Ijiroro: Kini yoo sele ti mo ba gbìyànjú láti ṣè imújáde àlàáfíà láti ínú wa? Kini mo gbalaye láti wa laarin emi ati Olórun? Kini ayédèrú làákàyè ààbòo timo ni láti ṣọ́ra fún? Kini àwọn ohun kékeré to lọ́gọ̀ sínú aye mi atipe tiwọn ba ewà àlàáfíà Olórun jẹ́?
Àwọn Àyọlò Òrọ̀ ti a mu lati Ìbáwí Kristiẹni ati kíkànilèkùn Ọlórun, © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org