Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Ọjọ́ 9 nínú 30

Nigbati Ọlórun gbé àwọ̀ èèyàn wọ̀ ninu Jésù Kristi fun idi ìwẹ̀nùmọ́ ésè, awon èniyàn won ko ri ohun tiwon yo nife lara e. Ṣugbọn nigba ti o ba de o̩kàn ẹlẹ́ṣẹ̀, o je ipo o̩kàn ti o ni oye idi to fi se pàtàkì fun Olórun lati gbe awo èyàn wo. Ipo to buriju ti eda lewa ni ki o mani íyọ̀ọ́nú tabi Ìdánilójú ẹ́ṣẹ̀, gbogbo ohun ma kunfun ayo ati àlàáfíà, sugbon o ti ku ni pátápátá si gbogbo àkóso ohun ti Jésù durofun.

Opolopo lara wa je aláìnírònù jinlẹ̀, a ko bikita ori wa nipa òdodo. Ati mu wa pẹ̀lú ìtùnú gangan, pẹ̀lú ìròrùn gangan ati àlàáfíà, atipe nigbati Èmí Olórun ba wole ti o dà ìwàdéédéé aye wa láàmú a ma fé lati paá ohun ti o ba se iṣípayá e tì.

Àwọn Ìbéèrè Ijiroro: Kí nìdí tí ti àlàáfíà tikò fidimulẹ leṣekú pani? Kí nìdí tí ti àlàáfíà to ròrùn sewa fúngbà díẹ̀? Kí nìdí tí ti ìtùnú seje ota àlàáfíà?

A yo áwọn oro wonyi lati Mimu Áwọn Ọmọ wá si Ogo ati Ẹkọ nipa Ìràpadà, © Olùtẹ̀jáde Ile Awọn Awari

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 8Ọjọ́ 10

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.

More

A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org