Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Ọjọ́ 13 nínú 30

Ọkàn ti o ṣokunkun jẹ ohun tin bani lẹru, nitori ọkàn ti o ṣokunkun le mu eniyan ni àlàáfíà. Eniyan aso wipe—“Ọkàn mi kìí ṣe búburú, idálẹbi fun ẹṣẹ kosi fummi; gbogbo oro nipa didi atunbi ati kíkún fún ẹ̀mí mímọ́ je oro tió bọ́gbọ́nmu.”Ọkàn lasan nilo Ihinrere ti Jesu, ṣugbọn ko fẹran rẹ, yoo ja lodi si rẹ, oma mú ìdánilójú ti ẹ̀mí Ọlọrun lati mu okunrin ati obirin ri wipe wo nilo lati ni iriri iṣẹ-ṣiṣe to jinle ti oore-ọfẹ ninu ọkàn wọn.

Awon igba kan wa nigbati àlàáfíà atinúwa ma duro lori aimokan; sugbon nigba ti aba jisi awọn iṣoro ti aye, eyiti o ju titélèlo ru ati rọ́sókèsódò ninu ihalẹ̀ mọ́ ìgbòkun, alaafia inu ko ṣeeṣe ayafi ti o gba lati ọdọ Oluwa wa. Nigba ti Oluwa wa sọ àlàáfíà, o ṣe àlàáfíà. Njẹ o ti gba ohun ti O sọ ri?

Ìbéère Ìdánilẹkọọ: irú àlàáfíà mo ni moni? Se irú towa lati ijewo eni ti mo je ati wíwà ni ilaja pẹlu Ọlọrun tabi lati aibikita eni ti mo je ati gbigbe ni ìsẹ́ra?
Amu awon ọrọ lati inu ẹkọ Bibeli ati imọran Kristeni© Olùtẹ̀jáde Ile Awari

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 12Ọjọ́ 14

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.

More

A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org