Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
An soro nipa alafia Jésù, sugbon se ati mo bi alafia seje bi? Eka itan igebse aye re, ogbon odun to lo ni iteriba ni nazareti ati odun meta ninu ise iyin rere, awon oro odi tiwon so si ati awon tiko nife re, won soro e lehin ati pe won tun korira re sibe ofara da gbogbo e, lailero o buru ju gbogbo nnkan ti aledoju ko laye lo, sibe alafia e o damu, oun wonyi ko wara alafia e. Olohun ma jogun re ni orun fun wa, kokinse bi iru alafia yi sugbon alafia yi gangan. Ninu gbogbo rudurudu aye, wiwa ati gbe aiye, ninu itele teni bawa ni ti ara laye, ibikibi ti Olohun bafu idojuko rampe eni si "Alafia Mi" tia o le damu, tia o le bagija ni Jesu tin fifun wa ni gbogbo aye wa.
Ifowokan yin ni agabra atijo na sibe, Baba efowo kan mi, kin le wa ni idapo pelu Yin titi gbogbo ara mi ma fi man tan fun Ayo ati Alafia Yin.
Awon Ibere Ijiroro: Se o ni alafia tole farada gbogbo idojuko ikorira re ati awon oro eri tiwon sosi e? Kini oun na to le damu alafia re? Atiwipe kinidi?
A mu iwe lati ijogun titan ati kikokun ilekun Olohun©

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org