Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Ọjọ́ 21 nínú 30

Lẹ́yìn ígbà tí èèyàn ti di atunbí a ni irírí àlàáfíà, sùgbọ́n oje àlàáfíà ni ìdásí ti ojú ogun. Èrò àìtọ́ kò tún gòkè mo, sùgbọ́n o wà níbẹ̀, atipe àwon èèyàn mọ̀. O mò nipa irírí àfirọ́pò mìíràn, nígbà mìíràn o wa nínù ayọ̀ púpọ̀ jọjọ, nígbà mìíràn nínú ìdọ̀tí; kosi idurodeede, kosi ayò ìṣẹ́gun ti èmí ni òtítọ́. Láti gba eyíí gẹ́gẹ́ bi irírí to kun fun ìgbàlà ni láti fi hàn pè Olórun ko ni àwíjàre ní ètùtù naa.

Láti je onígbàgbọ́ nínú Jésù Kristi túmọ̀si mimọ̀ wipé ohun ti Jésù so fun Tọmaasi je òtítọ́: “Émi ni ọ̀nà, òtítọ́, ati ìyè.” Jésù kii se ọ̀nà ti a n fi sílẹ̀ sẹ̀hìn bí a nse rìn ìrìn àjò, sùgbọ́n Ònà naa fúnra rẹ̀. nípasẹ̀ ígbàgbọ́, a wọnú ìsimi àlàáfíà naa, mímọ́, ati ìyè àìnípẹ̀kun nítorí a ngbé nínú Rè.

Ìbéèrè Ijiroro: Irú àlàáfíà wo ni an fipá jèrè? Kilo gba láti dì irú àlàáfíà naa mú? Kinidi ti ìfohùnṣọ̀kan pèlú Olórun se pàtàkì fun ojúlówó àlàáfíà?

Awọn Àyọlò Òrọ̀ ti a mu Láti Ìlànà Ìwà Híhù Ti Bíbélì ati Ìtẹ́wọ́gbà Si Olórun © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́

Ọjọ́ 20Ọjọ́ 22

Nípa Ìpèsè yìí

Oswald Chambers: Peace - Life in the Spirit

Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.

More

A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org