Oswald Chambers: Àlàáfíà - Ìgbésí Ayé nínù ÈmíÀpẹrẹ
Àlàáfíà ti ríronú je ẹ̀rí tó ga jù lọ fun wíwa ni òtún pèlù Olórun, nítorí mo wa ni òmìnira làti yi ókàn mi si Olórun. Bí mikọ́ báwa ni òtún pèlú Olórun mi kole yi ókàn mi síbikíbi ayafi si ara mi. Se ó ni ìdààmú ìrora nìsinsìnyí gan, oni ìpínyà ọkàn nípá àwon ìjì ati àwon ìgbòkun ti ìṣamọ̀nà ìgbaniláàyè ti Olórun? ní yíyí sórí, gẹ́gẹ́ bíi o ti ṣe jẹ́, àfọ́kù àpáta ti ígbàgbọ́ rè, Njé iwọ koi ti ri àlàáfíà tàbí ayò tàbí ìtùnú—gbogbo ohun yàgàn? Gbójú sókè ki o gba àìní ìyọlẹ́nu ti Olúwa wa Jésù Kristi. lókè àti ni òkodoro òtítọ́ ti ogun àti ìrora àti àwon ìṣòro rírí Ó jọba, pèlú àlàáfíà.
Ki Émì Olórun to mu àlàáfíà ókàn Ó ni láti mú gbogbo pàǹtí kúrò, kí Ó tó le sebe Ó ni láti fun wa ni ìròiyè inú pàǹtí to wà níbè.
Ìbéèrè Ijiroro: Kí ni àwon èrò ìmọtara-ẹni-nìkan sọ fún mi nípa èròǹgbà mi nípa àlàáfíà? Kí ni àwon èrò àníyàn timo ní-lò làti mu kúrò ni ókàn mi kí tó le ni àlàáfíà pélù Olórun àti àwon ẹlomìíràn?
Awọn Àyọlò Òrọ̀ ti a mu Láti Èkọ́ Kristeni ati Ìransé bi Olúwa Rè © Olùtẹ̀jáde Ni Ilé Àwárí

Ìwé mímọ́
Nípa Ìpèsè yìí
Àlàáfíà: Ìgbésí ayé ninu Èmí je ìṣúra àyọlò ọ̀rọ̀ lábẹ́ ìmísí lati àwon isé Oswald Chambers, akowe ìfọkànsìn to je olùfẹ́ ọ̀wọ́n àgbáyé òònkọ̀wé ati olùkọ̀wé ti Sísa Gbogbo Ipámi Fun Tí Ó Ga Jù Lọ. Ri ìsimi ninu Olórun atipe jèrè óye to jinlé nípa ìjépàtàkì àlàáfíà Olórun ígbésí ayé e.
More
A fe lati dupe lowo Olùtẹ̀jáde Ile Awari fun ipese eto yi. Fun alaye siwaju sii, jọwọ lọsi: www.utmost.org